Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Àfikún Ìsọfúnni Láti Lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

 18-A

Òwò Ṣíṣe àti Ọrọ̀ Ajé

Òwò Ṣíṣe àti Ọrọ̀ Ajé
WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán
 • Òṣùwọ̀n Nǹkan Olómi

 • Kọ́ọ̀ (Báàfù 10 / 60 hínì)

  220 Lítà / Gálọ́ọ̀nù 58.1

 • Báàfù (Hínì 6)

  22 Lítà / Gálọ́ọ̀nù 5.81

 • Hínì (Lọ́ọ̀gì 12)

  3.67 Lítà / Páìntì 7.75

 • Lọ́ọ̀gì (Hínì 1⁄12)

  0.31 Lítà / Páìntì 0.66

 • Òṣùwọ̀n Nǹkan Gbígbẹ

 • Hómérì (Kọ́ọ̀ 1 / Eéfà 10)

  220 Lítà / 200 kúọ̀tì

 • Eéfà (Séà 3 / Ómérì 10)

  22 Lítà / 20 kúọ̀tì

 • Séà (Ómérì 31⁄3)

  7.33 Lítà / Kúọ̀tì 6.66

 • Ómérì (Káàbù 14⁄5)

  2.2 Lítà / Kúọ̀tì 2

 • Káàbù

  1.22 Lítà / Kúọ̀tì 1.11

 • QKúọ̀tì

  1.08 Lítà / Kúọ̀tì 0.98

 •  Ìdíwọ̀n Nǹkan Gbọọrọ

 • Ọ̀pá esùsú gígùn (Ìgbọ̀nwọ́ gígùn 6)

  3.11 mítà / Ẹsẹ̀ bàtà 10.2

 • Esùsú (Ìgbọ̀nwọ́ 6)

  2.67 mítà / Ẹsẹ̀ bàtà 8.75

 • Fátọ́ọ̀mù

  1.8 mítà / Ẹsẹ̀ bàtà 6

 • Ìgbọ̀nwọ́ gígùn (Ìbú ọwọ́ 7)

  51.8 sẹ̀ǹtímítà / Ínǹṣì 20.4

 • Ìgbọ̀nwọ́ (Ìbú àtẹ́lẹwọ́ 2 / Ìbú ọwọ́ 6)

  44.5 sẹ̀ǹtímítà / Ínǹṣì 17.5

 • Ìgbọ̀nwọ́ kúkúrú

  38 sẹ̀ǹtímítà / Ínǹṣì 15

 • Sítédíọ̀mù Róòmù1

  Máìlì Róòmù 1⁄8= 185 mítà / Ẹsẹ bàtà 606.95

 1. 1 Ìbú ìka (Ìbú ọwọ́ 1⁄4)

  1.85 sẹ̀ǹtímítà / Ínǹṣì 0.73

 2. 2 Ìbú ọwọ́ (Ìbú ìka 4)

  7.4 sẹ̀ǹtímítà / Ínǹṣì 2.9

 3. 3Ìbú àtẹ́lẹwọ́ (Ìbú ọwọ́ 3)

  22.2 sẹ̀ǹtímítà / Ínǹṣì 8.75