WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

Àwọn Ọba Ìjọba Apá Gúúsù (A ti ń bá a bọ̀)

777 Ṣ.S.K.

Jótámù: ọdún 16

762

Áhásì: ọdún 16

746

Hesekáyà: ọdún 29

716

Mánásè: ọdún 55

661

Ámónì: ọdún 2

659

Jòsáyà: ọdún 31

628

Jèhóáhásì: oṣù 3

Jèhóákímù: ọdún 11

618

Jèhóákínì: oṣù 3, ọjọ́ 10

617

Sedekáyà: ọdún 11

607

Nebukadinésárì ọba Bábílónì àtàwọn èèyàn rẹ̀ ṣígun wá, wọ́n sì pa Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpìlì rẹ̀ run. Wọ́n mú Sedekáyà, ọba ìlà Dáfídì tó jẹ kẹ́yìn lórí ilẹ̀ ayé kúrò lórí ìtẹ́

 Àwọn Ọba Ìjọba Apá Àríwá (A ti ń bá a bọ̀)

n. 803 Ṣ.S.K.

Sekaráyà: àkọsílẹ̀ fi hàn pé oṣù 6 lo fi jọba

Sekaráyà bẹ̀rẹ̀ sí í jọba lọ́nà kan ṣáá, àmọ́ ẹ̀rí fi hàn pé nǹkan bí ọdún 792 ni ìjọba náà tó di tirẹ̀

n. 791

Ṣálúmù: oṣù 1

n. 780

Ménáhémù: ọdún 10

Pekaháyà: ọdún 2

n. 778

Pékà: 20 ọdún

n. 758

Hóṣéà: ọdún 9 láti n. bíi 748

n. 748

Ó jọ pé ìṣàkóso Hóṣéà fìdí múlẹ̀ dáadáa tàbí pé ó rí ìtìlẹ́yìn gbà látọ̀dọ̀ ọba Ásíríà, Tigilati-pílésà Kẹta ní nǹkan bí ọdún 748

740

Ásíríà ṣẹ́gun Samáríà, ó tẹ Ísírẹ́lì lórí ba; ìjọba ẹ̀yà mẹ́wàá àríwá Ísírẹ́lì dópin

 • Orúkọ Àwọn Wòlíì

 • Aísáyà

 • Míkà

 • Sefanáyà

 • Jeremáyà

 • Náhúmù

 • Hábákúkù

 • Dáníẹ́lì

 • Ìsíkíẹ́lì

 • Obadáyà

 • Hóséà