WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

Àwọn Ọba Ìjọba Júdà Ẹ̀yà Méjì Tó Wà ní Apá Gúúsù

997 Ṣ.S.K.

Rèhóbóámù: ọdún 17

980

Ábíjà (Ábíjámù): ọdún 3

978

Ásà: ọdún 41

937

Jèhóṣáfátì: ọdún 25

913

Jèhórámù: ọdún 8

n. 906

Ahasáyà: ọdún 1

n. 905

Ọbabìnrin Ataláyà: ọdún 6

898

Jèhóáṣì: 40 ọdún

858

Amasáyà: ọdún 29

829

Ùsáyà (Asaráyà): ọdún 52

 Àwọn Ọba Ìjọba Ísírẹ́lì Ẹ̀yà Mẹ́wàá Tó Wà ní Apá Àríwá

997 Ṣ.S.K

Jèróbóámù: ọdún 22

n. 976

Nádábù: ọdún 2

n. 975

Bááṣà: ọdún 24

n. 952

Éláhì: ọdún 2

Símírì: ọjọ́ 7 (n. 951)

n. 947

Ómírì àti Tíbínì: ọdún 4

Ómírì (nìkan): ọdún 8

n. 940

Áhábù: ọdún 22

n. 920

Ahasáyà: ọdún 2

n. 917

Jèhórámù: ọdún 12

n. 905

Jéhù: ọdún 28

876

Jèhóáhásì: ọdún 14

n. 862

Jèhóáhásì àti Jèhóáṣì: ọdún 3

n. 859

Jèhóáṣì (nìkan): ọdún 16

n. 844

Jèróbóámù Kejì: ọdún 41

  • Orúkọ Àwọn Wòlíì

  • Jóẹ́lì

  • Èlíjà

  • Èlíṣà

  • Jónà

  • Ámósì