Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ October 2015 | Àǹfààní Wo Lo Máa Rí Tó O Bá Ń Gbàdúrà?

Òǹkọ̀wé kan sọ pé ńṣe ni àdúrà “dà bí ìgbà téèyàn ń bá ohun ọ̀sìn rẹ̀ sọ̀rọ̀.” Ṣé òótọ́ lọ̀rọ̀ yìí?

COVER SUBJECT

Kí Nìdí Táwọn Èèyàn Fi Ń Gbàdúrà?

Ohun táwọn èèyàn ń gbàdúrà fún lè yà ẹ́ lẹ́nu.

COVER SUBJECT

Ṣé Ẹnì Kan Wà Tó Ń Gbọ́ Àdúrà?

Kí Ọlọ́run tó lè gbọ́ àdúrà wa, ohun méjì pàtàkì wà tá a gbọ́dọ̀ ṣe.

COVER SUBJECT

Ìdí Tí Ọlọ́run Fi Fẹ́ Ká Máa Gbàdúrà sí Òun

Àdúrà máa ń jẹ́ ká láwọn àǹfààní kan téèyàn kò lè rí láti ibòmí ì.

COVER SUBJECT

Àǹfààní Tó O Máa Rí Nínú—Àdúrà

Tó o bá ń gbàdúrà déédéé, àǹfààní wo ló máa ṣe fún ẹ?

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Àwọn ìṣòro wo ni Hẹ́rọ́dù kójú nígbà tó fẹ́ tún tẹ́ńpìlì Jerúsálẹ́mù kọ́? Kí nìdí táwọn ará ìlú Málítà fi ronú pé apààyàn ni àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù?

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Mo Ti Lè Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́ Báyìí

Ìjàǹbá burúkú kan ṣẹlẹ̀ sí Julio Corio, ó sì rò pé Ọlọ́run kò rí tòun rò. Ẹ́kísódù 3:7 ràn án lọ́wọ́ láti tún èrò rẹ̀ ṣe.

Ǹjẹ́ A Lè Mọ Ọlọ́run?

Àwọn nǹkan tí a kò mọ̀ nípa Ọlọ́run lè mú kó o túbọ̀ sún mọ́ Ọlọ́run sí i.

ANCIENT WISDOM FOR MODERN LIVING

Máa Dárí Jini Látọkànwá

Tá a bá fẹ́ dárí jini, ṣé ká kàn fojú pa ohun tẹ́nì kan ṣe rẹ́ tàbí ká ṣe bíi pé kò dùn wá?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ta ló lè fòpin sí ìṣẹ́ àti òṣì?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Ní Bíbélì Sọ Nípa Ibi Tí Ọdún Halloween Ti Wá?

Ṣé nǹkan tí kò burú ni ọdún Halloween àbí ohun tó burú ni?