Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ September 2015 | Ta Ni Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Tó o bá fẹ́ mọ ìdáhùn, o ò ṣe béèrè lọ́wọ́ àwọn tọ́rọ̀ náà kàn?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ta Ni Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Ṣé èrò àwọn tá a mẹ́nu kàn nínú àpilẹ̀kọ yìí bá tìẹ mu?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Irú Èèyàn Wo Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Ibi tó o ti máa pàdé wa lè yà ẹ́ lẹ́nu.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Gbọ́?

Ìdánilójú tá a ní nínú Bíbélì ló pinnu ohun tá a gbà gbọ́.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Báwo La Ṣe Ń Rówó Bójú Tó Iṣẹ́ Wa?

Ibo ni owó tá à ń ná ti wá? Báwo la ṣe ń lò ó?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Nìdí Tá A Fi Ń Wàásù?

Ìdí mẹ́ta ló fà á tá a fi ń wàásù kárí ayé.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Mo Rí Ohun Tó Sàn Ju Òkìkí

Mina Hung Godenzi di olókìkí lọ́sàn kan òru kan, àmọ́ ayé rẹ̀ kò rí bó ṣe rò.

Bíbélì Bedell—Bíbélì Tó Mú Káwọn Èèyàn Túbọ̀ Lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

Ọgọ́rùn-ún mẹ́ta ọdún ni kò fi sí ìtumọ̀ Bíbélì mí ì ní èdè Irish.

Ṣé O Ronú Pé Ọlọ́run Ti Já Ẹ Kulẹ̀?

Ǹjẹ́ o ti rò ó rí pé, ‘Kí nìdí tí Ọlọ́run fi jẹ́ kí irú èyí ṣẹlẹ̀ sí mi?’

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Àǹfààní wo ni àwọn àsọtẹ́lẹ̀ inú Bíbélì ṣe wá?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Ni Ogun Amágẹ́dọ́nì?

Ẹ̀ẹ̀kan péré ni ọ̀rọ̀ náà Amágẹ́dọ́nì fara hàn nínú Bíbélì, àmọ́ Ìwé Mímọ́ sọ̀rọ̀ gan-an nípa ogun tí ọ̀rọ̀ náà tọ́ka sí.