Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ August 2015 | Ṣé Àwọn Tó Ti Kú Lè Jíǹde?

Kì í kàn ṣe pé Bíbélì dáhùn ìbéèrè yẹn nìkan, ó tún fún wa ní ẹ̀rí tó dájú tó máa mú ká gba ohun tó sọ gbọ́.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ Lẹ́yìn Ikú?

Bíbélì sọ nípa àwọn mẹ́jọ tó jíǹde. Kí ni wọ́n sọ pé ó ṣẹlẹ̀ nígbà tí wọ́n kú?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ǹjẹ́ Ìrètí Wà fún Àwọn Tó Ti Kú?

Kí nìdí tí Ọlọ́run fi máa jí àwọn aláìṣòdodo dìde?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Bó Ṣe Lè Dá Ẹ Lójú Pé—Àjíǹde Àwọn Òkú Máa Wà?

Bíbélì fún wa ní ẹ̀rí méjì tó fẹsẹ̀ múlẹ̀ tó mú ká gbà pé àjíǹde dájú.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Jèhófà Fi Àánú Hàn Sí Mi Ju Bí Mo Ṣe Rò Lọ

Félix Alarcón rí nǹkan gidi fi ìgbésí ayé rẹ̀ ṣe lẹ́yìn tí ìjàǹbá alùpùpù mú kó rọ lápá àtẹsẹ̀.

TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN

“Mo Dìde Gẹ́gẹ́ Bí Ìyá ní Ísírẹ́lì”

Kí ni ìtàn Dèbórà kọ́ wa nípa ohun tó túmọ̀ sí láti ní ìgbàgbọ́?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kí nìdí tá a fi wà láyé? Kí nìdí tí Ọlọ́run fi dá èèyàn?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Báwo Lo Ṣe Lè Borí Ìbẹ̀rù Ikú?

Wàá gbádùn ìgbésí ayé rẹ tó o bá borí ìbẹ̀rù ikú tí kò bọ́gbọ́n.