Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ April 2015 | Se Waa Fe Kekoo Bibeli?

Opo eeyan kari aye lo n janfaani ninu ikekoo Bibeli tawa Elerii Jehofa n se fawon eeyan lofee. Wo bi awon eko Bibeli se le se e lanfaani.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ki Nidi To Fi Ye Ko O Kekoo Bibeli?

Nje o ti ronu ri pe, ‘Mi o ki i raye,’ tabi ‘Mi o feran ki n maa sadehun’?

Eto Eko Bibeli fun Gbogbo Eeyan

Wo idahun si mejo lara awon ibeere ti awon eeyan maa n beere nipa eto ikonilekoo yii.

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Ibeere Meta Lo Yi Igbesi Aye Mi Pa Da

Doris Eldred to je oluko ri idahun si awon ibeere re nipa igbesi aye nigba ti akekoo re kan ko o lekoo Bibeli.

Ohun Siseyebiye Ti Won Ri Ninu Pantiri

Ajaku orepete Rylands ti Ihin Rere Johanu wa ninu re ni iwe afowoko ti Iwe Mimo Kristeni Lede Giriiki ti ojo re pe ju lo.

A CONVERSATION WITH A NEIGHBOR

Ki Nidi To Fi Ye Ka Maa Se Iranti Iku Jesu?

Opo eeyan maa n se ayeye ojo ibi Jesu nigba odun Keresimesi ati ajinde re nigba Odun Ajinde. Ki nidi ti Awon Elerii Jehofa fi maa n se iranti iku Jesu dipo iyen?

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Kí ni iṣẹ́ balógun ọ̀rún nínú ẹgbẹ́ ọmọ ogun Róòmù? Kí ni ìyàtọ̀ tó wà nínú dígí tí wọ́n ń lò láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì àti tòde òní?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ǹjẹ́ gbogbo èèyàn kárí ayé lè nífẹ̀ẹ́ ara wọn?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni Bíbélì Ti Wá?

Ọ̀pọ̀ àwọn tó kọ Bíbélì sọ pé Ọlọ́run ló darí àwọn láti kọ́ ohun táwọn kọ. Kí nìdí?