Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ March 2015 | Jesu Gba Wa—Lowo Ki Ni?

Se owo Esu lo ti gba wa, abi lowo ibinu Olorun, abi lowo nnkan mii?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Idi Ti A Fi Nilo Igbala

Nje Olorun to nifee wa maa da wa pe ko maa wu wa lati gbe ile aye titi lae, ko tun wa mu ki o maa see se fun wa?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Iku ati Ajinde Jesu—Anfaani To Se fun E

Bibeli so awon otito mefa to fi bi iku okunrin kan se maa mu iye wa fun opolopo.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Iranti Iku Jesu ibi ta a ti maa se e ati igba ta a maa se e

Lodun 2015, ojo Friday, April 3, ni iranti iku Kristi bo si leyin ti oorun ba ti wo.

ÀWỌN ÒǸKÀWÉ WA BÉÈRÈ PÉ

Se O Ye Ki Awon Kristeni Maa Se Ayeye Odun Ajinde?

Ki lawon opitan so nipa ayeye to gbajumo yii?

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Oju Jairo—Mu Ko Le Sin Olorun

Inu Jairo maa n dun, igbesi aye re si nitumo laika pe arun inu opolo to le ju lo n ba a finra.

Nje O Mo?

Anfaani wo ni apositeli Poolu ri ninu jije omo ibile Roomu? Bawo ni won se n sanwo ise fun awon oluso aguntan laye igba ti won n ko Bibeli?

Ebun To To Si Oba

Awon eroja yii le wopo lonii, amo won won to wura nigba ti won n ko Bibeli.

Ohun Ti Bibeli So

Awon wo lo ye ko je buredi ati waini nigba Iranti Iku Jesu?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Máa Jọ́sìn Àwọn Ère?

Ǹjẹ́ Ọlọ́run fẹ́ ká máa lo àwọn ère nínú ìjọsìn wa?