Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ August 2014 | Ǹjẹ́ Ọlọ́run Bìkítà Nípa Rẹ?

Báwo ni Ọlọ́run ṣe ń fi hàn pé òun bìkítà nípa wa?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ǹjẹ́ Ọlọ́run Máa Ń Ronú Nípa Rẹ?

Ǹjẹ́ Ọlọ́run Olódùmarè máa ń ronú nípa rẹ?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ọlọ́run Máa Ń Bójú Tó Ẹ

Kí nìdí tí Bíbélì fi pé Jèhófà ni ‘Ọlọ́run tó rí ohun gbogbo’?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ọ̀rọ̀ Rẹ Yé Ọlọ́run

Kì í ṣe àwọn àṣìṣe rẹ ni Ọlọ́run ń wá tó bá ń wo inú ọkàn rẹ.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ọlọ́run Ń Tù Ẹ́ Nínú

Tí ìṣòro rẹ bá rí bíńtín lẹ́gbẹ̀ẹ́ ti ọ̀kẹ́ àìmọye àwọn èèyàn tí ìṣòro wọn gadabú ńkọ́?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ọlọ́run Fẹ́ Kí O Sún Mọ́ Òun

Tó bá jẹ́ pé o gba Ọlọ́run gbọ́ àmọ́ tó ń ṣe ẹ́ bíi pé o jìnnà sí i ńkọ́?

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Mo Fẹ́ Gba Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Ìwà Ìrẹ́jẹ àti Ìwà Ipá

Antoine Touma gbóná nínú ìjà Kọnfú, àmọ́ Ìwé 1 Tímótì 4:8 tún ayé rẹ̀ ṣe.

TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN

“Ẹ jọ̀wọ́, Ẹ Fetí Sí Àlá Tí Mo Lá”

Wàhálà tó wà nínú ìdílé Jósẹ́fù jẹ́ ẹ̀kọ́ fáwọn ìdílé tó tún ìgbéyàwó ṣe.

ÀWỌN ÒǸKÀWÉ WA BÉÈRÈ PÉ

Ta Ló Dá Ọlọ́run?

Ṣé ó bọ́gbọ́n mu kéèyàn gbà pé kò sígbà tí Ọlọ́run kò sí?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ṣé òótọ́ ni pé ọ̀pọ̀ ìsìn ò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Ẹni Gidi Ni Ọlọ́run?

Bíbélì sọ pé Ọlọ́run lo agbára rẹ̀ láti dá ohun gbogbo, àmọ́ ṣe ó tiẹ̀ bìkítà nípa wa?