Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ July 2014 | Kí Nìdí Tí Nǹkan Burúkú Fi Ń Ṣẹlẹ̀ Sáwọn Èèyàn Rere?

Ṣé Ọlọ́run ló fà á ni? Àbí Kámà? Ọ̀nà wo la fi lè bọ́ lọ́wọ́ ibi yìí?

COVER SUBJECT

Àjálù Gbòde Kan!

Tó bá jẹ́ lóòótọ́ ni Olódùmarè wà, kí nìdí tí kò fi dáàbò bo àwọn èèyàn rere kúrò nínú ewu

COVER SUBJECT

Kí Nìdí Tí Nǹkan Burúkú Fi Ń Ṣẹlẹ̀ Sáwọn Èèyàn Rere?

Bíbélì sọ ìdí mẹ́ta pàtàkì tó fà á ti a fi ń jìyà.

COVER SUBJECT

Ohun Tí Ọlọ́run Máa Ṣe Láti Fòpin Sí Ìwà Búburú

Ǹjẹ́ ó wù ẹ́ láti gbé nínú ayé kan tí ìwà burúkú kò ti ní ṣẹlẹ̀ sí àwọn èèyàn rere mọ́?

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Ìbọn Máa Ń Wà Lára Mi Níbikíbi Tí Mo Bá Lọ

Annunziato Lugarà wà nínú ẹgbẹ́ ọmọọ̀ta kan, àmọ́ lílọ tó lọ sí Gbọ̀ngàn Ìjọba yí ayé rẹ̀ pa dà.

Bí O Ṣe Lè Bá Àwọn Ọmọ Rẹ Wí

Bíbélì sọ ohun mẹ́ta tó máa mú kí ìbáwí yọrí sí rere.

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Báwo ni àwọn atukọ̀ ṣe máa ń ṣe ọkọ̀ wọn kí omi má bàa wọlé? Báwo ni wọ́n ṣe máa ń tọ́jú ẹja láyé àtijọ́ kó má bàa bàjẹ́ ?

Báwo La Ṣe Lè Rí Ọlọ́run?

Kọ́ bí o ṣe lè lo “ojú ọkàn-àyà rẹ.”

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kì í ṣe nítorí àti béèrè fún ìrànlọ́wọ́ nìkan la ṣe ń gbàdúrà sí Ọlọ́run

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Ọlọ́run Ló Ń Fi Àwọn Àjálù Jẹ Àwa Èèyàn Níyà?

Ṣàgbéyẹ̀wò àwọn nǹkan mẹ́ta tí Bíbélì sọ, tó ń jẹ́ ká mọ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.