Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ June 2014 | Ojú Tí Ọlọ́run fi Ń Wo Sìgá Mímu

Tó o bá mọ ojú tí Ọlọ́run fi ń wo sìgá mímu lè mú kó o jáwọ́.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ìṣòro Kan Tó Kárí Ayé

Kí nìdí tí ìṣòro sìgá fi ń peléke sí i láìka ìsapá àwọn èèyàn láti fòpin sí i?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ojú Wo ni Ọlọ́run fi Ń Wo Sìgá Mímu?

Báwo la ṣe máa mọ̀ nígbà tí Bíbélì ò dárúkọ sìgá?

Ǹjẹ́ O ti Jẹ Búrẹ́dì Tí Ń Fúnni Ní Ìyè?

Kí nìdí tí Jésù fi pe ara rẹ̀ ní búrẹ́dì ìyè àti búrẹ́dì láti ọ̀run?

Ìrètí Wo Ló Wà fún Àwọn Baba Ńlá Mi Tó ti Kú?

Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ pé Ọlọ́run yóò jí àwọn aláìṣòdodo dìde. Kí nìdí tí Ọlọ́run á fi ṣe bẹ́ẹ̀?

Àwọn Mẹ́ta Tó Wá Òtítọ́ Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Kẹrìndínlógún—Kí Ni Wọ́n Rí?

Capito, Cellarius àti Campanus ṣe ohun kan tó sọ wọ́n di ọ̀ta Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólí ìkì àtí àwọn Alátùn-únṣe Ìsìn.

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ǹjẹ́ ìdí tí Ọlọrun fi dá ayé yóò nímùúṣẹ?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Ọlọ́run Ló Fa Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé?

Ìpọ́njú lè bá ẹnikẹ́ni, títí kan àwọn tí Ọlọ́run ṣojú rere sí pàápàá. Kí nìdí?