Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ April 2014 | Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí O Máa Gbàdúrà?

Tí Ọlọ́run bá mọ nǹkan tá a fẹ́, ṣó tún yẹ ká máa gbàdúrà? Bíbélì dáhùn ìbéèrè yìí.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Nìdí Tí Àwọn Èèyàn Fí Máa Ń Gbàdúrà?

Àwọn tí kò tiẹ̀ gba Ọlọ́run gbọ́ gan-an ń gbàdúrà. Kí nìdí?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí O Máa Gbàdúrà?

Ọlọ́run lè dáhùn àdúrà wa láìjẹ́ pé ó ṣe iṣẹ́ ìyanu.

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Bíbélì Ni Wọ́n Fi Dáhùn Gbogbo Ìbéèrè Mi!

Isolina Lamela jẹ́ mọdá ní ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì, ó pa dà dí Kọ́múníìsì, ṣùgbọ́n méjèèjì tojú sú u. Ó pàdé àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó fi Bíbélì ràn lọ́wọ́ láti gbé ìgbésí ayé tó dáá.

O Borí Ìdẹwò!

Àwọn nǹkan mẹ́ta kan wà tó o lè ràn ẹ́ lọ́wọ́.

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Ní ilẹ̀ Róòmù àtijọ́, kí ni wọ́n máa ń ṣe fún àwọn ẹrú tó bá jẹ́ ìsáǹsá? Kí nìdí tó fi jẹ́ pé aró aláwọ̀ àlùkò ti ilẹ̀ Tírè ló wọ́n jù láyé?

Thomas Emlyn—Asọ̀rọ̀ òdì àbí Olùgbèjà Òtítọ́?

Àwọn ìwádìí tó ṣe látinú Bíbélì sọ ọ́ di ọ̀tá pẹ̀lú àwọn ọmọ ìjọ rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Ireland àti ní Ilé ẹjọ́ gíga wọn.

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Jésù ti gbé ìgbésẹ̀ láti mú kí àlááfíà wà lórí ilẹ̀ ayé.

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Dá Wa?

Ǹjẹ́ o máa ń ronú pé, ‘Kí nìdí tí Ọlọ́run fi dá wa?’ Wo bí Bíbélì ṣe dáhùn ìbéèrè yìí.