Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ March 2014 | Ohun tí Ọlọ́run ti Ṣe fún Ẹ

Ọlọ́run ló fún wa ní ìwàláàyè àti àwọn nǹkan tó ń mú ká gbádùn ayé wa, àmọ́, ṣe kò ju àwọn nǹkan wọ̀nyẹn náà lọ?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ohun Tí Ọlọ́run Ti Ṣe Fún Ẹ

Ìlànà Ọlọ́run tó sọ pé “ẹ̀mí fún ẹ̀mí” ló jẹ́ ká mọ ìdí tí Ọlọ́run fi “fi Ọmọ bíbí rẹ̀ kan ṣoṣo fúnni.”

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Kan Tó Yẹ Kó Ṣojú Ẹ

Jọ̀wọ́ dara pọ̀ mọ́ wa láti ṣe Ìrántí Ikú Jésù.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Bí Mo Tiẹ̀ Jẹ́ Aláìlera, Okun Inú Ń Gbé Mi Ró

Obìnrin kan tó wà lórí kẹ̀kẹ́ arọ máa ń rí “agbára tí ó ré kọjá ìwọ̀n ti ẹ̀dá” nítorí ìgbàgbọ́ rẹ̀.

Ǹjẹ́ Ọlọ́run Fẹ́ Kí Àwọn Ẹ̀sìn Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ Máa Jọ́sìn Pa Pọ̀?

Ṣé dandan ni kí ìrẹ́pọ̀ wà láàárín gbogbo àwọn ẹlẹ́sìn ni? Ohun tí Bíbélì sọ lè yà ọ́ lẹ́nu.

Bí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ṣe dé Orílẹ̀ èdè Sípéènì

Ìfara jọra wo ló wà láàárín àwọn iléèwé tó ń da Ìwé Mímọ́ kọ sórí síléètì àti àwọn tó ń f ìgboyà gbé Bíbélì kọjá ni àwọn ibi tí wọ́n ti fòfin dè é?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Báwo ni ikú ẹ̀ṣẹ̀ Ádámù àti ikú Jésù ṣe tan mọ́ra wọn?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ọdún Àjíǹde?

Kà nípa ibi tí àṣà Ọdún Àjíǹde márùn-ún ti wá.