Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ February 2014 | Ogun Tó Da Ayé Rú

Kí nìdí tí ogun àgbáyé Kìíní fi sọ ilẹ̀ ayé dìdàkudà? Ǹjẹ́ àwọn ìdáhùn náà sọ nǹkan kan fún wa nípa ọjọ́ ọ̀la wa?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ogun Tó Da Ayé Rú

Báwo ni ogun àgbáyé Kinní tí wọ́n tún ń pè ní “Ogun Ńlá” ṣe da ayé rú lọ́nà tó ṣì fi kàn wá títí dòní?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ẹni Tó Wà Lẹ́yìn Ogun àti Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé

Báwo ni Bíbélì ṣe fi hàn pé ogun tó wáyé ní ọ̀run tan mọ́ ogun àgbáyé àti wàhálà tó ń ṣẹlẹ̀ lórí ilẹ̀ ayé?

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

“Ìlérí Párádísè Yí Ìgbésí Ayé Mi Pa Dà”

Ọ̀gbẹ́ni kan tó ń jẹ Ivars Vigulis gbádùn òkìkí àti ògo tó wà nínú fifi alùpùpù díje. Báwo ni ẹ̀kọ́ Bíbélì ṣe tún ayé rẹ̀ ṣe?

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Álóè wo ni álóè tí wọ́n máa ń lò láyé ìgbà tí wọ́n kọ Bíbélì? Irú àwọn ọrẹ ẹbọ wo ni àwọn àlùfáà máa ń gbà nínú Tẹ́ńpìlì?

ÀWỌN ÒǸKÀWÉ WA BÉÈRÈ PÉ

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Fàyè Gba Ìnilára?

Bíbélì sọ ohun tí Ọlọrun ń ṣe nípa ìwà ìkà nísinsìnyí àti ohun tó máa ṣe lọ́jọ́ iwájú.

TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN

Ó Fara Da Ìwà Ìrẹ́jẹ

Ṣé àwọn èèyàn ti rẹ́ ìwọ náà jẹ rí? Ṣé ó wù ẹ́ láti rí kí Ọlọ́run mú ọ̀ràn tọ́? Wo bó o ṣe lè fara wé Èlíjà tó jé olóòótọ́.

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ǹjẹ́ ẹ̀rí wà pé ọ̀dọ́ Ọlọ́run ni Bíbélì ti wá? Báwo ni wọ́n ṣe kọ ọ́?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Nìdí Tí Kò Fi Sí Àlàáfíà Ní Ayé?

Gbogbo ìsapá àwọn èèyàn láti mú kí àlàáfíà wà ní ayé ti já sí pàbó. Gbé àwọn ohun tó fà á yẹ̀ wò.