Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ January 2014 | Ǹjẹ́ Ikú Ni Òpin Ìgbésí Ayé Ẹ̀dá?

Ọ̀rọ̀ nípa ikú kì í dùn ún sọ. Ọ̀pọ̀ èèyàn kì í fẹ́ sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀. Wọ́n máa ń rò pé àwọn ò ní kú. Ǹjẹ́ a lè ṣẹ́gun ikú?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Oró Ikú

Bó pẹ́ bó yá ó lè kan wá tàbí àwọn tó sún mọ́ wa. Oró tí ikú ń dáni ti mú kí ọ̀pọ̀ èèyàn fẹ́ láti mọ ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà tá a bá kú.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Aráyé Ń Sapá Kí Wọ́n Lè Ṣẹ́gun Ikú

Ọjọ́ pẹ́ táwọn èèyàn ti ń wá bí wọ́n ṣe máa ṣẹ́gun ikú. Ǹjẹ́ èyí ṣeé ṣe?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ikú Kọ́ Ni Òpin Ìgbésí Ayé Ẹ̀dá!

Kí nìdí tí Jésù ṣe fi ikú wé oorun? Kí lá rí kọ́ nínú àkọsílẹ̀ àjíǹde tó wà nínú Bíbélì?

ÌJÍRÒRÒ LÁÀÁRÍN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ ÀTI ẸNÌ KAN

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run fi Fàyè Gba Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé?

Ìwé àkọ́kọ́ nínú Bíbélì ṣàlàyé ìdí tí Ọlọ́run ṣì fi fàyè gba àwọn ohun búburú tó ń ṣẹlẹ̀, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ní agbára láti fòpin sí i.

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Báwo ni wọ́n ṣe ń fi ọrẹ ṣètìlẹyìn nínú tẹ́ńpìlì nígbà ayé Jésù? Ṣé òpìtàn tí ọ̀rọ̀ rẹ̀ péye ni Lúùkù tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tó kọ Bíbélì?

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

“Jèhófà Kò Tíì Gbàgbé Mi”

Obìnrin kan tí kì í fọ̀rọ̀ ẹ̀sìn ṣeré rí ìdáhùn sí ìbéèrè rẹ̀ nípa ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà tí èèyàn bá kú. Kà nípa bí òtítọ́ ṣe yí ìgbésí ayé rẹ̀ pa dà.

Àjíǹde—Ni Ìrètí Tó Wà Fún Àwọn Òkú

Kí nìdí táwọn àpọ́sítélì Jésù fi ní ìgbàgbọ́ tó dájú nínú àjíǹde àwọn òkú?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

lo mọ̀ nípa Ọlọ́run? Báwo la ṣe lè kọ́ bí a ṣe lè mọ Ọlọ́run dáadáa?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Ni Ọlọ́run Fẹ́ Kí N Fi Ayé Mi Ṣe?

Ǹjẹ́ o nílò kí Ọlọ́run fi àmì àrà ọ̀tọ̀ kan hàn ọ́ tàbí kí Ọlọ́run bá ọ sọ̀rọ̀ kó o tó mọ bí wàá ṣe máa ṣe ìfẹ́ rẹ̀? Ka ohun tí Bíbélì sọ.