Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ December 2013 | Ǹjẹ́ A Nílò Ọlọ́run?

Èrò ọ̀pọ̀ èèyàn ni pé àwọn kò nílò Ọlọ́run, àwọn mí ì sì rò pé ọwọ́ àwọn dí ju pé káwọn ṣẹ̀ṣẹ̀ máa ronú nípa Ọlọ́run. Ǹjẹ́ àǹfààní kankan tiẹ̀ wà nínú kéèyàn mọ Ọlọ́run?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Nìdí Tí Ìbéèrè Yìí Fi Jẹ Yọ?

Wo díẹ̀ lára ìdí tí ọ̀pọ̀ àwọn tó sọ pé àwọn gba Ọlọ́run gbọ́ kì í fi í ṣe ìpinnu tó fi hàn pé wọ́n gbà pé Ọlọ́run wà lóòótọ́.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ìdí Tá A Fi Nílò Ọlọ́run

Kọ́ nípa bí a ṣe lè láyọ̀ kí ìgbésí ayé wa sì ládùn tí a bá sún mọ́ Ọlọ́run.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Iṣẹ́ Jèhófà Ni Mo Fi Ìgbésí Ayé Mi Ṣe

Ìwọ̀nba oṣù díẹ̀ ló kù kí Bill Walden gboyè jáde bí ẹnjiníà tó ń ya àwòrán ilé, àmọ́ ó pinnu láti fi ayé rẹ̀ ṣe nǹkan gidi. Kà nípa bí ìgbésí ayé rẹ̀ ṣe yí pa dà nígbà tó yan iṣẹ́ Ọlọ́run.

SÚN MỌ́ ỌLỌ́RUN

“Wò ó! Mo Ń Sọ Ohun Gbogbo Di Tuntun”

Ṣé ó wù ẹ́ láti gbé nínú ayé tí ìrora, ìpọ́njú àti ikú á ti di ohun àtijọ́? Mọ̀ nípa bí Ọlọ́run ṣe máa mú ìlérí rẹ̀ ṣẹ.

‘Láti Inú Àwọn Òkè Ńlá Ni Ìwọ Yóò Ti Máa Wa Bàbà’

Ohun tí àwọn awalẹ̀pìtàn ṣàwárí lẹ́nu àìpẹ́ yìí jẹ́ ká mọ̀ nípa bí wọ́n ṣe lo bàbà láyé ìgbà tí wọ́n kọ Bíbélì.

KỌ ỌMỌ RẸ

?

Ṣé ọmọ jòjòló ṣì ni Jésù? Ta ni àwọn “amòye” tí wọ́n wá wo Jésù? Kí ni Jésù ń ṣe báyìí?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kí nìdí tí Jésù fi ń pa dà bọ̀? Ṣé gbogbo ojú ni yóò rí Jésù tó bá pa dà dé, kí ló sì máa ṣe?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì