Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ October 2013 | Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?

Bíbélì jẹ́ ká mọ bá a ṣe dé ayé àti bí Ọlọ́run ṣe ṣètò láti dá aráyé nídè nípasẹ̀ Mèsáyà.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Ka Bíbélì?

Bíbélì kì í ṣe ìwé tó kàn sọ nípa Ọlọ́run, àmọ́ ó tún jẹ́ ìwé tó ti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá. Kí ni o lè rí kọ́ nínú rẹ̀?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Báwo La Ṣe Dé Ayé?

Ní kúkúrú, Jẹ́nẹ́sísì tó jẹ́ ìwé àkọ́kọ́ nínú Bíbélì ṣàlàyé bí ayé àti ọ̀run ṣe bẹ̀rẹ̀. Kí ni a tún lè rí kọ́ nínú ìwé Jẹ́nẹ́sísì?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Bí Ọlọ́run Ṣe Dá Aráyé Nídè

Báwo ni ìlérí tí Ọlọ́run ṣe fún Ábúráhámù ṣe kan Mèsáyà náà? Mọ̀ nípa bí Ọlọ́run ṣe máa gba aráyé sílẹ̀ lọ́wọ́ àìsàn, ìyà àti ikú.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

“Àwa Ti Rí Mèsáyà Náà”!

Ọ̀pọ̀ ló gbà pé Jésù ni Mèsáyà tí Ọlọ́run ṣèlérí. Àwọn kan kò gbà bẹ́ẹ̀. Wo ohun tí Bíbélì sọ.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ìròyìn Ayọ̀ Fún Gbogbo Èèyàn

Àǹfààní wo ni ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run bá wa sọ nínú Bíbélì lè ṣe fún wa lónìí àti ní ọjọ́ iwájú?

Bó O Ṣe Lè Máa Gbé Ayé Rẹ Lọ Lẹ́yìn Ìkọ̀sílẹ̀

Ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé gbogbo àwọn tó ti kọ ara wọn sílẹ̀ ló máa ń rí i pé nǹkan le fún àwọn lẹ́yìn ìkọ̀sílẹ̀ ju bí àwọn ṣe rò lọ. Àwọn ìmọ̀ràn Bíbélì wúlò, á jẹ́ kó o lè kojú ìṣòro rẹ

SÚN MỌ́ ỌLỌ́RUN

“Jèhófà Dárí Jì Yín Fàlàlà”

Tọkàntọkàn ni Ọlọ́run máa ń dárí ji àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ tó bá ronú pìwà dà. Kí lo yẹ kí èyí mú kí àwa náà máa ṣe sí àwọn èèyàn? Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì ká máa dárí jini?

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

“Ọ̀pọ̀ Èèyàn Ló Kórìíra Mi”

Kà nípa bí ọkùnrin oníwà ipá kan ṣe kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tó sì di èèyàn àlàáfíà.

Báwo Ni Àwọ̀ Ṣe Ń Nípa Lórí Rẹ?

Àwọ̀ lè nípa lórí bí nǹkan ṣe ń rí lára àwa èèyàn. Jẹ́ ká gbé àwọ̀ mẹ́ta kan yẹ̀ wò àti ipa tí wọ́n lè ní lórí rẹ.

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ìrètí wo ló wà fún àwọn tó ti kú? Ǹjẹ́ wọ́n tún lè wà láàyè?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Nìdí Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Fi Ń Lọ Láti Ilé Dé Ilé?

Kọ́ nípa ohun tí Jésù sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀ pé kí wọ́n máa ṣe.