Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ September 2013 | Kí Nìdí Tí Ìyà Fi Pọ̀ Láyé? Ìgbà Wo Ló Máa Dópin?

Kí ni Bíbélì sọ nípa ìyà tó ń jẹ àwa èèyàn, báwo ló sì ṣe máa nípa lórí aráyé tó?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Àìmọye Aláìṣẹ̀ Ló Ti Ṣègbé!

Aráyé ń jìyà láìsí ìdí kan tó ṣe gúnmọ́. Ṣẹ́ ẹ̀bi Ọlọ́run ni?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí nìdí tí ìyà fi pọ̀ tó báyìí?

Mọ àwọn ohun márùn ún tó fa ìyà lónìí, àti ibi tí a ti lè rí ojúlówó ìrètí.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ìyà Máa Dópin Láìpẹ́!

Ọlọ́run ti ṣèlérí pé òun má mú gbogbo ohun tó ń fa ìyà kúrò. Báwo ló ṣe máa ṣe é, ìgbà wo sì ni?

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Tálákà Ni Wá àmọ́ À Ń Fi Ayọ̀ Sin Ọlọ́run

Alexander Ursu rí i pé kò sẹ́ni tó lè dá ìjọsìn Ọlọ́run dúró, kódà ìjọba Soviet Union àtijọ́ kò lè dá a dúró. Ka ìtàn alárinrin kan nípa ìtàn ìgbésí ayé ẹnì yìí.

Ṣé Ilé Gogoro Bábélì Ni Èdè Wa Ti Bẹ̀rẹ̀?

Kí ni ilé Gogoro Bábélì? Níbo ni èdè àwa èèyàn ti ṣẹ̀ wá?

DRAW CLOSE TO GOD

“Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Olùfúnni Ọlọ́yàyà”

Wádìí nípa ohun tó yẹ ká ní lọ́kàn tá a bá ń fúnni ní nǹkan.

KỌ ỌMỌ RẸ

Ohun Tí O Bá Ṣe Lè Dùn Ọlọ́run—Bí O Ṣe Lè Mú Inú Rẹ̀ Dùn

Ǹjẹ́ o mọ̀ pé ohun tí o bá ṣe lè mú kí inú Ọlọ́run dùn tàbí kó bà á nínú jẹ́? Mọ̀ nípa ohun tí Ádámù àti Éfà ṣe tí ó dun Jèhófà.

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Àwọn ìmọ̀ràn Bíbélì nípa bí tọkọtaya ṣe lè láyọ̀ wúlò gan-an, torí pé Jèhófà Ọlọ́run tó ṣètò ìgbéyàwó ló fún wa ni àwọn ìmọ̀ràn náà.

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Báwo Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣe Ń Rówó Ná fún Iṣẹ́ Wọn?

Mọ̀ nípa bí iṣẹ́ ìwàásù kárí ayé ṣe ń gbilẹ̀ sí i láìjẹ́ pé à ń gbé igbá owó tàbí san ìdámẹ́wàá.