Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ August 2013 | Àwòrán Oníhòòhò—Ó Léwu Àbí Kò Léwu

Ǹjẹ́ àwòrán oníhòòhò léwu àbí kò léwu? Kí lo lè ṣe tó ò fi ní máa wo àwòrán oníhòòhò mọ́?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Àwòrán Oníhòòhò—Ó Léwu Àbí Kò Léwu?

Ọṣẹ́ wo ni àwòrán oníhòòhò ń ṣe fún ẹni tó ń wò ó àti fún ìdílé?

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

“Mo Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ronú Gidigidi Nípa Ibi Tí Mo Ń Bọ́rọ̀ Ayé Mi Lọ”

Ka bí àwọn ìlànà inú Bíbélì ṣe ran ọkùnrin kan lọ́wọ́ kó lè jáwọ́ nínú àṣà tó ti mọ́ ọn lára, tó sì yí èrò rẹ̀ pa dà kó lè máa ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run.

OUR READERS ASK

Kí Nìdí Tí Bíbélì Fi Sọ̀rọ̀ Nípa Àwọn Kan Àmọ́ Tí Kò Dárúkọ Wọn?

Ǹjẹ́ a lè sọ pé gbogbo àwọn tí Bíbélì ò dárúkọ wọn kò jámọ́ nǹkan kan tàbí pé wọ́n jẹ́ èèyàn burúkú?

DRAW CLOSE TO GOD

‘Àwọn Ànímọ́ Rẹ̀ Tí A Kò Lè Rí Ṣe Kedere’

Ǹjẹ́ o gbà pé Ọlọ́run wà? Ǹjẹ́ o mọ àwọn ẹ̀rí tó fi hàn pé Ọlọ́run wà?

TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN

Ọlọ́run Pa Nóà “Mọ́ Láìséwu Pẹ̀lú Àwọn Méje Mìíràn”

Báwo ni Ọlọ́run ṣe dáàbò bo Nóà àti ìdílé rẹ̀ ní àkókò tó tíì le jù nínú ìtàn ẹ̀dá?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kí nìdí tí inú Ọlọ́run kì í fi í dún sí àwọn àdúrà kan? Kí la gbọ́dọ̀ ṣe kí Ọlọ́run tó gbọ́ àdúrà wa?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ǹjẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Yẹra Fún Àwọn Tí Kò Ṣe Ẹ̀sìn Wọn Mọ́?

Nígbà míì, ó máa ń pọn dandan pé ká yọ ẹnì kan lẹ́gbẹ́, èyí sì lè ran irú ẹni bẹ́ẹ̀ lọ́wọ́ láti pa dà sínú ìjọ.