Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ June 2013 | Ìgbà Wo Ni Ẹ̀tanú Máa Dópin?

Ọlọ́run nìkan ló lè mú kí ẹ̀tanú àti kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà kásẹ̀ nílẹ̀ pátápátá. Ìgbà wo ló máa ṣe é, báwo ló sì ṣe máa ṣe é?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ìwà Ẹ̀tanú—Ìṣòro Tó Kárí Ayé

Kí ni ẹ̀tanú? Kí nìdí tí a fi gbà pé kárí ayé ni ẹ̀tanú ń bá àwọn èèyàn fínra lẹ́nì kọ̀ọ̀kan?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ìgbà Wo Ni Ayé Yìí Máa Bọ́ Lọ́wọ́ Ẹ̀tanú?

Ìrírí àwọn tó jẹ́ ká mọ̀ pé Bíbélì ń ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ kí wọ́n lè borí ẹ̀tanú. Ìgbà wo ló máa dópin pátápátá?

SÚN MỌ́ ỌLỌ́RUN

Jèhófà “Kì Í Ṣe Ojúsàájú”

Ọlọ́run máa ń tẹ́tí sí àdúrà àwọn tó ń sìn ín, láìka ẹ̀yà wọn tàbí orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti wá tàbí ipò tí wọ́n wà láwùjọ sí. Báwo la ṣe mọ̀ bẹ́ẹ̀?

Ìṣura Kan Tó Fara Sin Láti Ọgọ́rọ̀ọ̀rún Ọdún

Wo bí wọ́n ṣe ṣàwárí Bíbélì tí àwọn èèyàn kà sí èyí tó tíì pẹ́ jù lọ lédè Georgian

Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Máa Gbàdúrà sí Àwọn Ẹni Mímọ́?

Ohun tí Bíbélì sọ nípa àdúrà sí àwọn ẹni mímọ́ máa jẹ́ ká rí ìdáhùn sí ìbéèrè yìí: Ǹjẹ́ ó yẹ ká máa bẹ̀rù láti gbàdúrà sí Ọlọ́run?

KỌ ỌMỌ RẸ

Kí La Rí Kọ́ Nínú Ohun Tó Ṣẹlẹ̀ sí Ọ̀daràn Kan?

Kí Jésù tó kú, ó ṣèlérí fún ọ̀daràn kan tó ń kú lọ lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ pé ó máa wà nínú Párádísè. Kí ni Jésù ní lọ́kàn? Báwo ni Párádísè yẹn ṣe máa rí?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Láìka bí àwọn èèyàn ṣe sa gbogbo ipá wọn tó, kò tíì ṣeé ṣe fún wọn láti mú kí àlàáfíà wà kárí ayé. Wo ohun tó fà á.

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Fàyè Gba Àwọn Ẹ̀sìn Míì?

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bí fífàyè gba àwọn míì ṣe ń jẹ́ ká mọ àwọn Kristẹni tòótọ́.