Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ March 2013 | Àǹfààní Tí Àjíǹde Jésù Ṣe Fún Wa

Ṣé àjíǹde Jésù lè ṣe ẹ́ láǹfààní lóde òní?

COVER SUBJECT

Ṣé Òótọ́ Ni Pé Jésù Jíǹde?

Níwọ̀n bí àjíǹde Jésù ti jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ẹ̀kọ́ Bíbélì, ó yẹ ká wádìí bóyá ó ṣẹlẹ̀ lóòótọ́.

COVER SUBJECT

Àjíǹde Jésù Máa Jẹ́ Ká Ní Ìyè Àìnípẹ̀kun!

Ìwọ rò ó wò ná, kéèyàn wà láàyè títí láé láìsí ìrora, ìyà àti ọ̀fọ̀ kankan.

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Báwo ni àwọn Júù ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní ṣe ń múra òkú sílẹ̀ kí wọ́n tó lọ sin ín? Ṣé bí àwọn Júù ṣe máa ń sìnkú ni wọ́n ṣe sin Jésù?

OUR READERS ASK

Ṣé Ọ̀run Ni Jésù Sọ Pé Aṣebi Tó Wà Lẹ́gbẹ̀ẹ́ Òun Yóò Lọ?

Jésù ṣèlérí fún aṣebi yẹn pé: “Ìwọ yóò wà pẹ̀lú mi ní Párádísè.” Kí ló ní lọ́kàn?

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

“Mo Rí I, Ṣùgbọ́n Kò Yé Mi”

Olivier ní ìṣòro àrà ọ̀tọ̀ torí pé ó jẹ́ adití. Wo bí Jèhófà ṣe ràn án lọ́wọ́.

DRAW CLOSE TO GOD

“Èwo Ni Èkínní Nínú Gbogbo Òfin?”

A lè fi gbólóhùn kan péré ṣe àkópọ̀ gbogbo ohun tí Ọlọ́run fẹ́ ká máa ṣe.

KỌ ỌMỌ RẸ

Pétérù Parọ́, Ananíà Náà Parọ́—Ẹ̀kọ́ Wo Ni Èyí Kọ́ Wa?

Wo ìdí tí ọ̀kan fi rí ìdáríjì gbà, àmọ́ tí èkejì kò rí gbà.

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kí nìdí tí wọ́n fi ń pe Jésù ní Ọmọ Ọlọ́run? Ìgbà wo ni Ọlọ́run dá a?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Kristẹni Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Jọ̀wọ́ ṣàgbéyẹ̀wò bí a ṣe yàtọ̀ sí àwọn míì tí wọ́n ń pè ní Kristẹni.