Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ February 2013 | Kí La Lè Rí Kọ́ Lára Mósè?

Wo mẹ́ta lára ìwà dáadáa tí Mósè ní àti ẹ̀kọ́ tí a lè rí kọ́ nínú àpẹẹrẹ rẹ̀.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ta Ni Mósè?

Ẹni ọ̀wọ̀ ni àwọn ẹlẹ́sìn Kristẹni, àwọn Júù, àwọn Mùsùlùmí àti àwọn míì ka Mósè ọkùnrin olóòótọ́ náà sí. Kí ni o mọ̀ nípa Mósè?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Mósè Jẹ́ Ẹni Tó Ní Ìgbàgbọ́

Ìgbàgbọ́ tí Mósè ní fẹsẹ̀ múlẹ̀ torí pé ó gbé ìgbé ayé rẹ̀ lọ́nà tó fi hàn pé ó ní ìgbàgbọ́ nínú àwọn ìlérí Ọlọ́run. Báwo lo ṣe lè ní irú ìgbàgbọ́ tí Mósè ní?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Mósè Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló máa ń wò ó pé òmùgọ̀ ni ẹni tó bá ní ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀. Irú ojú wo ni Ọlọ́run fi ń wo ìwà yìí? Báwo ni Mósè ṣe lo ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Mósè Jẹ́ Onífẹ̀ẹ́

Mósè fi hàn pé òun nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Ẹ̀kọ́ wo la rí kọ́ lára Mósè?

SÚN MỌ́ ỌLỌ́RUN

Ọlọ́run Àwọn Alààyè Ni

Ọlọ́run ní agbára láti jí àwọn tó ti kú dìde kó sì tipa bẹ́ẹ̀ sọ ikú dòfo. Kí ló jẹ́ kí ìlérí yìí dá wa lójú?

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

“Wọ́n Fẹ́ Kí Èmi Fúnra Mi wádìí Láti Mọ Ohun Tí Bíbélì Sọ”

Ó wu Luis Alifonso pé kó di míṣọ́nnárì ẹ̀sìn Mormon. Báwo ni ẹ̀kọ́ Bíbélì ṣe yí ayé rẹ̀ àti àwọn nǹkan tó fẹ́ ṣe ní ìgbésí ayé pa dà?

OHUN TÓ LÈ MÚ KÍ ÌDÍLÉ LÁYỌ̀

Ohun Tí Ẹ Lè Ṣe Tí Ọmọ Yín Bá Jẹ́ Abirùn

Jẹ́ ká wo àwọn ìṣòro mẹ́ta tó sábà máa ń jẹ yọ àti bí ọgbọ́n tó wà nínú Bíbélì ṣe lè mú kó o borí wọn.

Irú Ìwé Wo Ni “Ìhìn Rere Júdásì”?

Ṣé Júdásì ọmọ ẹ̀yìn tó da Jésù ló kọ ìwé ìhìn rere yìí? Ǹjẹ́ ó yẹ kí ọ̀rọ̀ inú ìwé yìí ní ipa lórí ojú tí a fi ń wo Kristi àti ẹ̀kọ́ tó kọ́ wa?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Níwọ̀n bó ti jẹ́ pé Ọlọ́run ló dá ohun gbogbo, ṣé òun náà ló dá Èṣù ni? Wo ohun tí Bíbélì sọ.

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Wàá Máa Ṣàánú?

Ṣèwádìí, kó o sì ronú jinlẹ̀ nípa àkàwé aláàánú ará Samáríà, kó o wá wo ẹ̀kọ́ tí o lè kọ́ nínú ìtàn náà.