Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) December 2015

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti February 1 sí 28, 2016 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

Ǹjẹ́ O Rántí?

Wò ó bóyá o ṣì rántí àwọn ohun tó wà nínú àwọn ẹ̀dà Ilé Ìṣọ́ tó jáde ní oṣù mẹ́fà sẹ́yìn.

Jèhófà Máa Ń Bá Àwa Èèyàn Sọ̀rọ̀

Bí Ọlọ́run ṣe mú kí wọ́n kọ ọ̀rọ̀ rẹ̀ sílẹ̀ lónírúurú èdè kọ́ wa ní ohun pàtàkì kan nípa rẹ̀.

Bíbélì Tó Rọrùn Láti Lóye

Ìlànà pàtàkì mẹ́ta ni Ìgbìmọ̀ Tó Túmọ̀ Bíbélì Ayé Tuntun tẹ̀ lé.

Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Tá A Tún Ṣe Lọ́dún 2013

Kí ni díẹ̀ lára àwọn àtúnṣe pàtàkì tá a ṣe sínú rẹ̀?

Máa Fi Ahọ́n Rẹ Sọ̀rọ̀ Tó Ń Gbéni Ró

Báwo ni àpẹẹrẹ Jésù ṣe lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ ìgbà tó yẹ kó o sọ̀rọ̀, ohun tó yẹ kó o sọ àti bó ṣe yẹ kó o sọ ọ́?

Jèhófà Yóò Gbé Ọ Ró

Tí àìsàn bá ń ṣe ẹnì kan, kí ló yẹ kó ṣe nípa rẹ̀?

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Mo Ní Àjọṣe Tó Dáa Pẹ̀lú Ọlọ́run àti Pẹ̀lú Màmá Mi

Nígbà tí Michiyo Kumagai pa ìjọsìn àwọn baba ńlá tì, àárín òun àti màmá rẹ̀ ò gún mọ́. Báwo ló ṣe wá pa dà ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú màmá rẹ̀?

Atọ́ka Àwọn Àkòrí fún Ilé Ìṣọ́ 2015

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a tẹ̀ jáde nínú ẹ̀dà Ilé Ìṣọ́ tá à ń fi sóde àtèyí tó wà fún ìkẹ́kọ̀ọ́ tá a tò ní ìsọ̀rí-ìsọ̀rí.