Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) September 2015

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti October 26 sí November 29, 2015 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

Ǹjẹ́ Ò Ń Dé Ìwọ̀n Ìdàgbàsókè Tó Jẹ́ Ti Kristi?

Bó ti wù kó pẹ́ tó tá a ti ń sin Jèhófà, a lè máa dàgbà nípa tẹ̀mí.

Ṣé Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ Ṣeé Gbára Lé?

Wàá rí bí ẹ̀rí ọkàn rẹ ṣe lè ràn ẹ́ lọ́w kó o lè ṣe ìpinnu tó mọ́gbọ́n dání tó bá kan ọ̀rọ̀ ìtọ́jú, eré ìtura àti iṣẹ́ ìwàásù.

‘Ẹ Dúró Gbọn-in Nínú Ìgbàgbọ́’

Kí ni bí Pétérù ṣe rìn lórí omi kọ́ wa nípa ìgbàgbọ́ wa?

Àwọn Ọ̀nà Wo Ni Jèhófà Ń Gbà Fìfẹ́ Hàn sí Wa?

Ǹjẹ́ ó máa ń ṣòro fún ẹ láti lóye tàbí láti gbà pé Jèhófà fẹ́ràn rẹ?

Báwo La Ṣe Lè Fi Hàn Pé A Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà?

Kì í ṣe ọ̀rọ̀ ẹnu lásán.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Ìbùkún Jèhófà Mú Kí Ìgbésí Ayé Mi Túbọ̀ Nítumọ̀

Gbádùn ìtàn ìgbésí ayé arábìnrin Melita Jaracz tó ti lo ohun tó lé ní àádọ́ta ọdún lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ Ted Jaracz, tó jẹ́ ara Ìgbìmọ̀ Olùdarí.