Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) August 2015

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti September 28 sí October 25, 2015 wà nínú ilé ìṣọ́ yìí.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

“Kí Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Erékùṣù Máa Yọ̀”

Ka ìtàn ìgbésí ayé Geoffrey Jackson tó jẹ́ ara Ìgbìmọ̀ Olùdarí.

Máa Ṣe Àṣàrò Lórí Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Tí Jèhófà Ní sí Wa

Kí ló mú kó dá ẹ lójú pé Jèhófà kò ní fi ẹ́ sílẹ̀ kódà nígbà ìṣòro?

Ẹ Máa Bá A Nìṣó ní Fífojú Sọ́nà

Kí ni ìdí pataki méjì tó fi yẹ ká túbọ̀ máa ṣọ́nà bá a ṣe ń sún mọ́ òpin ètò àwọn nǹkan yìí?

Máa Gbé Ìgbé Ayé Tó O Máa Gbé Nínú Ayé Tuntun Báyìí

A lè fi àwọn èèyàn Ọlọ́run wé àwọn tó fẹ́ kó kúrò ní orílẹ̀-èdè kan lọ sí orílẹ̀-èdè míì.

Ṣọ́ Àwọn Tó Ò Ń Bá Kẹ́gbẹ́ ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn Yìí

Kì í ṣe àwọn tó máa ń wà pẹ̀lú ẹ nìkan lò ń bá kẹ́gbẹ́.

Kí La Lè Rí Kọ́ Látinú Àpẹẹrẹ Jòánà?

Ìyípadà wo ló ṣe ní ìgbésí ayé rẹ̀ kó lè máa tẹ̀ lé Jésù?

LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA

“Jèhófà Mú Yín Wá sí Ilẹ̀ Faransé Láti Kẹ́kọ̀ọ́ Òtítọ́”

Ìwé àdéhùn tí ìjọba orílẹ̀-èdè Poland àti ti ilẹ̀ Faransé ti ọwọ́ bọ̀ ní ọdún 1919 ní àbájáde tí wọn kò rò tẹ́lẹ̀.