Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) May 2015

Awon apileko ta a maa kekoo lati June 29 sí July 26, 2015 lo wa ninu eda yii.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Ife Ti Mo Ni fun Olorun Latibere Mu Ki N Le Fara Da A

Waa gbadun itan igbesi aye Arakunrin Anthony Morris III, to je okan lara Igbimo Oludari ti awa Elerii Jehovah.

Sora!—Satani Fe Pa O Je

Three characteristics of Satan make him an especially dangerous enemy.

O Le Ba Satani Ja—Ko o si Bori!

Bawo lo se le sora fun awon nnkan ti Satani fi n dekun muni, iru bi igberaga, kiko ohun ini tara jo ati isekuse?

Won “Ri” Awon Ohun Ti Olorun Seleri

Awon okunrin ati obinrin igbaani ti won je olooto fi apeere rere lele ni ti bi won se n foju inu yaworan awon ibukun ti Olorun seleri.

E Fara We Eni To Seleri Iye Ainipekun

Nje a le mo ipo kan ti ko tii sele si wa ri lara ni ti gidi?

Ibeere Lati Owo Awon Onkawe

Ta ni Googu ti ile Magogu ti iwe Isikieli soro nipa re?

LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA

O Ri I Pe Ife Lo Mu Ki Nnkan Wa Letoleto Nile Ijeun Naa

To ba je pe láti awon odun 1990 si 1999 tabi leyin igba naa lo to bere si i lo si apejo agbegbe awa Elerii Jehofa, a wu e lori láti ko nipa awon ohun ta a maa n se lawon apejo ta a ti se ni opo odun seyin.