Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) February 2015

Awon apileko ta a maa kekoo lati April 6 si May 3, 2015 lo wa ninu eda yii.

Ebun Pataki Kan To Wa fun Awon Ara Japan

A gbe iwe tuntun kan ta a pe akori re ni,‘The Bible—The Gospel According to Matthew’ jade lede Japan. Awon ohun wo lo wa ninu iwe yii? Ki nidi ti eto Olorun fi se e?

E Je Onirele ati Onijelenke Bii Ti Jesu

Iwe 1 Peteru 2:21 gba wa niyanju pe ka te le awon isise Jesu pekipeki. Ba a tie je alaipe, bawo la se le je onirele ati onijelenke bii ti Jesu?

E Je Onigboya Ke E si Maa Lo Ifoyemo Bii Ti Jesu

Bibeli je ka mo iru eni ti Jesu je. Wo ba a se le te le isise re ta a ba je onigboya ta a si ni ifoyemo bii tire.

Maa Fi Itara Waasu Niso

A mo pe ise pipolongo ihin rere Ijoba Olorun ni ise to se pataki ju ti a le se lonii. Bawo la se le mu ki itara wa po si i, ka si maa fi itara waasu niso?

Mimura Awon Orile-Ede Sile fun “Eko Jehofa”

Aseyori wo lawon Kristeni orundun kinni se lenu ise iwaasu ihin rere? Ki lo see se ko mu ki ise iwaasun rorun ni orundun kinni ju awon igba mii lo jale itan?

Jehofa N Dari Ise Ikonilekoo Ti A N Se Kari Aye

Ki lawon nnkan to ti sele lode oni to je kawon iranse Jehofa le waasu ihin rere naa lona to muna doko kari aye?

Ibeere Lati Owo Awon Onkawe

Ki la le se ka le ran awon arakunrin ati arabinrin ti oorun lofinda maa n da laamu lowo? Igba wo lo maa pon dandan pe ki arabinrin kan to je akede Ijoba Olorun bo ori re?

LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA

“Akoko Ta A Moyi Ju Lo”

Iwe iroyin Zion’s Watch Tower so pe Iranti Iku Kristi je “akoko ta a moyi ju lo,” o si ro awon to n ka a pe ki won se iranti yii. Bawo ni won se n se Iranti Iku Kristi nigba yen lohun un?