Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) January 2015

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti March 2 sí April 5, 2015 ló wà nínú ẹ̀dá yìí.

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—ní New York

Kí nìdí tí tọkọtaya kan tó rí towó ṣe fi kó kúrò nínú ilé ńlá tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí gan-an, tí wọ́n sì kó lọ sí yàrá kékeré kan?

Fi Ọpẹ́ Fún Jèhófà Kí O sì Gba Ìbùkún

Bó o bá moore Jèhófà, báwo nìyẹn ṣe lè jẹ́ kó o fara da ìdẹwò?

Ìdí Tí A Fi Ń Lọ Síbi Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa

Báwo lo ṣe máa mọ̀ bóyá Ọlọ́run ti fún ẹ ní ìrètí ti ọ̀run tàbí ti ilẹ̀ ayé?

Bí Tọkọtaya Ṣe Lè Ṣera Wọn Lọ́kan Kí Wọ́n sì Láyọ̀

Ohun márùn-ún tó máa mú kí tọkọtaya ṣe ara wọn lọ́kan, kí ìgbéyàwó wọn lè wà pẹ́ títí.

Jẹ́ Kí Jèhófà Dáàbò Bo Ìgbéyàwó Rẹ Kó sì Fún Un Lókun

Àwọn nǹkan wo ló lè ṣe kó o lè yẹra fún panṣágà àti aburú tó lè gbẹ̀yìn rẹ̀?

Ǹjẹ́ Ìfẹ́ Àárín Tọkọtaya Lè Wà Pẹ́ Títí?

Bí Orin Sólómọ́nì ṣe ṣàpèjúwe ìfẹ́ jẹ́ ẹ̀kọ́ pàtàkì fáwọn tó fẹ́ ṣègbéyàwó àti tó ti gbéyàwó.