Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) June 2014

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti August 4 sí 31, 2014 ló wà nínú ẹ̀dá yìí.

“Mú Ipa Ọ̀nà Ẹsẹ̀ Rẹ Jọ̀lọ̀” Kó O Lè Tẹ̀ Síwájú

Báwo lo ṣe lè mú ohun ìdíwọ́ kúrò kí ọwọ́ rẹ sì tẹ àfojúsùn tẹ̀mí rẹ?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Ṣó yẹ kí àwọn Kristẹni máa sun òkú?

Báwo La Ṣe Lè Ran Àwọn Kristẹni Tí Ọkọ Tàbí Ìyàwó Wọn Kọ̀ Sílẹ̀ Lọ́wọ́?

Mọ bó o ṣe lè lóye àwọn ìṣòro táwọn tí wọ́n kọ̀ sílẹ̀ máa ń dojú kọ.

“Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run Rẹ”

Kẹ́kọ̀ọ́ ohun tí Jésù ní lọ́kàn nígbà tó ní ká fi gbogbo ọkàn-àyà, ọkàn àti èrò inú wa nífẹ̀ẹ́ Jèhófà.

“Nífẹ̀ẹ́ Aládùúgbò Rẹ Gẹ́gẹ́ Bí Ara Rẹ”

Kí ni Jésù ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé ká nífẹ̀ẹ́ aládùúgbò wa? Báwo la ṣe lè ṣe bẹ́ẹ̀?

Ǹjẹ́ O Rántí?

Ṣó o ti fara balẹ̀ ka àwọn Ilé Ìṣọ́ tó jáde lẹ́nu àìpẹ́ yìí? Wò ó bóyá wàá lè dáhùn àwọn ìbéèrè yìí.

Ṣé Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Àìlera Ẹ̀dá Ni Ìwọ Náà Fi Ń Wò Ó?

O lè máa fi ojú tó tọ́ wo àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin tó dà bí aláìlera.

Ran Àwọn Mìíràn Lọ́wọ́ Láti Lo Ẹ̀bùn Wọn ní Kíkún

Báwo la ṣe lè ran àwọn ọ̀dọ́kùnrin àtàwọn arákùnrin tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣèrìbọmi lọ́wọ́ kí wọ́n lè tẹ̀ síwájú?