Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ilé Iṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)  |  December 2013

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 2013

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 2013

Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

 • A Ti Sọ Yín Di Mímọ́, 8/15

 • Àwọn Alàgbà Jẹ́ ‘Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ fún Ìdùnnú Wa,’ 1/15

 • Àwọn Ìránnilétí Jèhófà Ṣeé Gbẹ́kẹ̀ Lé, 9/15

 • Báwo La Ṣe Lè Máa Ní “Ẹ̀mí Ìdúródeni”? 11/15

 • Dúró sí Ibi Ààbò Jèhófà, 2/15

 • Èyí Ni Ogún Tẹ̀mí Wa, 2/15

 • ‘Èyí Yóò sì Jẹ́ Ìrántí fún Yín,’ 12/15

 • Ẹ̀kọ́ Tó Wà Nínú Àdúrà Tí Wọ́n Ronú Jinlẹ̀ Gbà, 10/15

 • Ẹ Má Ṣe Jẹ́ Kí Àárẹ̀ Mú Yín, 4/15

 • Ẹ Má Ṣe “Tètè Mì Kúrò Nínú Ìmọnúúrò Yín”! 12/15

 • Ẹ Máa Bá Ara Yín Sọ̀rọ̀ Kẹ́ Ẹ Lè Túbọ̀ Ṣera Yín Lọ́kan, 5/15

 • Ẹ Máa Gba Ti Ara Yín Rò Kẹ́ Ẹ sì Máa fún Ara Yín Ní Ìṣírí, 8/15

 • “Ẹ Máa Sìnrú fún Jèhófà,” 10/15

 • “Ẹ Máa Ṣe Èyí ní Ìrántí Mi,” 12/15

 • Ẹ Máa Wádìí Dájú Àwọn Ohun Tí Ó Ṣe Pàtàkì Jù, 4/15

 • ‘Ẹ Wà Lójúfò Kí Ẹ Lè Máa Gbàdúrà,” 11/15

 • Ẹ̀yin Òbí Àtẹ̀yin Ọmọ, Ẹ Máa Fìfẹ́ Bá Ara Yín Sọ̀rọ̀, 5/15

 • Ẹ̀yin Olùṣọ́ Àgùntàn, Ẹ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Ńlá Náà, 11/15

 • Fi Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ran Ara Rẹ àti Àwọn Míì Lọ́wọ́, 4/15

 • Iṣẹ́ Aṣáájú-Ọ̀nà Máa Jẹ́ Kó O Túbọ̀ Sún Mọ́ Ọlọ́run, 9/15

 • Ìṣẹ̀dá Ń Jẹ́ Ká Mọ̀ Nípa Ọlọ́run Alààyè, 10/15

 • Jàǹfààní Kíkún Látinú Kíka Bíbélì Déédéé, 4/15

 • Jèhófà Ni Ibùgbé Wa, 3/15

 • Jésù Ń Tipasẹ̀ Àwọn Èèyàn Kéréje Bọ́ Ọ̀pọ̀ Èèyàn, 7/15

 • Jẹ́ Adúróṣinṣin Kó O sì Máa Dárí Jini Bíi Ti Jèhófà, 6/15

 • Jẹ́ Kí Amọ̀kòkò Tí Kò Lẹ́gbẹ́ Náà Mọ Ẹ́, 6/15

 • Jẹ́ Kí Àwọn Ìránnilétí Jèhófà Máa Múnú Rẹ Dùn, 9/15

 • Jẹ́ Onígboyà, Jèhófà Wà Pẹ̀lú Rẹ! 1/15

 • Jẹ́ Ọ̀làwọ́ Kó O sì Máa Fòye Báni Lò Bíi Ti Jèhófà, 6/15

 • ‘Kò Sí Ohun Ìkọ̀sẹ̀’ fún Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, 3/15

 • Má Ṣe Jẹ́ Kí Ohunkóhun Mú Ẹ Jìnnà sí Jèhófà, 1/15

 • Má Ṣe “Kún fún Ìhónú sí Jèhófà,” 8/15

 • Máa Fi Ọgbọ́n Ṣe Ìpinnu, 9/15

 • Máa Gbé Orúkọ Ńlá Jèhófà Ga, 3/15

 • Máa Ronú Nípa Irú Ẹni Tó Yẹ Kó O Jẹ́, 8/15

 • Máa Ṣe Ìpinnu Tó Dára Kó O Má Bàa Pàdánù Ogún Tẹ̀mí Rẹ, 5/15

 • ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

 • “Àwòrán Yìí Mà Dára Gan-an O!” 7/15

 • Ọ̀KAN-Ọ̀-JỌ̀KAN

 • Àfiwé Máa Ń Mú Kí Ọ̀rọ̀ Yéni, 9/15

 • Àjíǹde, 10/1

 • Àlááfíà Lórí Ilẹ̀ Ayé, 6/1

 • A ‘Polongo Rẹ̀ Ní Olódodo Nípa Àwọn Iṣẹ́’ (Ráhábù), 11/1

 • Àwòrán Oníhòòhò—Ó Léwu àbí Kò Léwu? 8/1

 • Àwọn Júù Máa Ń Ṣe Ìgbátí Yí Òrùlé Ilé Wọn Ká, 4/1

 • Àwọn Wo Ló Ń Lọ sí Ọ̀run? 11/1

 • Bá A Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ fún Àwọn Èèyàn, 11/15

 • Bàbà (ohun tí wọ́n lò ó fún látijọ̀), 12/1

 • Bí Àwọn Júù Ọgọ́rùn-ún Ọdún Kìíní Ṣe Ń Múra Òkú Sílẹ̀ Kí Wọ́n Tó Sin Ín, 3/1

 • Bí Àwọ̀ Ṣe Ń Nípa Lórí Rẹ, 10/1

 • Èlíṣà Rí Kẹ̀kẹ́ Ẹṣin Oníná, 8/15

 • Ẹ̀ṣọ́ Olú Ọba Gbọ́ Ìhìn Rere, 2/15

 • Ẹ̀tanú—Ìṣòro Tó Kárí Ayé, 6/1

 • Ìbátan Káyáfà Ni, 2/15

 • Ibi Tí Èṣù Ti Wá, 2/1

 • Ìdí Tí Bíbélì Kò Fi Dárúkọ Àwọn Kan, 8/1

 • Ìgbésí Ayé Lè Ládùn, 4/1

 • Ìhìn Rere Júdásì, 2/1

 • Kí Nìdí Tí Ìyà Fi Pọ̀ Láyé? 9/1

 • Mósè, 2/1

 • Nínéfè “Ìlú Ńlá Ìtàjẹ̀sílẹ̀,” 4/1

 • Ǹjẹ́ Èèyàn Lè Wà Láàyè Títí Láé? 7/1

 • Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Máa Gbàdúrà sí Àwọn Ẹni Mímọ́? 6/1

 • Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kí O Gbára Lé Ẹ̀sìn? 7/1

 •