Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) December 2013

Ẹ̀dà yìí sọ ohun tá a lè ṣe tí ohunkóhun kò fi ní jin ìgbàgbọ́ wa lẹ́sẹ̀. Láfikún, ìgbà wo ló yẹ ká máa ṣe Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa, kí ló sì túmọ̀ sí fún wa?

Jèhófà Dáàbò Bò Wọ́n Lábẹ́ Òjìji Àwọn Òkè Ńlá

Báwo làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní Jámánì ṣe ń rí ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ gbà lásìkò ìjọba Násì? Ewu wo làwọn ará náà kojú?

Ẹ Má Ṣe “Tètè Mì Kúrò Nínú Ìmọnúúrò Yín”!

Àwọn ìkìlọ̀ tó bọ́ sákòókò wo ló wà nínú lẹ́tà kejì tí Pọ́ọ̀lù kọ sáwọn Kristẹni tó wà ní Tẹsalóníkà? Kí ni kò ní jẹ́ kí wọ́n tàn wá jẹ?

Ṣé Wàá Yááfì Àwọn Nǹkan Torí Ìjọba Ọlọ́run?

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bá a ṣe lè lo owó, okun àti ẹ̀bùn àbínibí wa láti ṣètìlẹ́yìn fún Ìjọba Ọlọ́run.

Ǹjẹ́ O Rántí?

Ṣó o ti fara balẹ̀ ka àwọn Ilé Ìṣọ́ tó jáde lẹ́nu àìpẹ́ yìí? Dán ara ẹ wò bóyá wàá rántí.

‘Èyí Yóò Jẹ́ Ìrántí Fún Yín’

Kí lohun táwa Kristẹni gbọ́dọ̀ mọ̀ nípa Ìrékọjá? Kí ni Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa túmọ̀ sí fún gbogbo wa?

“Ẹ Máa Ṣe Èyí Ní Ìrántí Mi”

Báwo la ṣe máa ń mọ ìgbà tó yẹ ká ṣe Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa? Kí ni búrẹ́dì àti wáìnì náà dúró fún?

Bí O Ṣe Lè Fara Da Ikú Ọkọ Tàbí Aya Rẹ

Ikú ọkọ tàbí aya ẹni máa ń fa ìrora ńlá tí kì í tán bọ̀rọ̀. Wo bí àjíǹde tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ní ká máa retí ṣe jẹ́ ohun ìtùnú.

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 2013

Wo atọ́ka àwọn àkòrí àwọn àpilẹ̀kọ tá a tẹ̀ jáde nínú Ilé Ìṣọ́ Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 2013.