Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) May 2013

Ìwé yìí sọ bá a ṣe lè ṣe ojúṣe wa bí ajíhìnrere. Ó tún sọ ohun tó yẹ kí ìdílé ṣe láti máa bá ara wọn sọ̀rọ̀.

Ṣe Ojúṣe Rẹ Gẹ́gẹ́ Bí Ajíhìnrere

Kí nìdí tó fi dáa káwọn èèyàn gbọ́ ìhìn rere? Báwo la ṣe lè máa ṣe ojúṣe wa gẹ́gẹ́ bí ajíhìnrere tó mọṣẹ́?

Ǹjẹ́ O Ní Ìtara Fún “Iṣẹ́ Àtàtà”?

Àpilẹ̀kọ yìí sọ bí ìtara wa lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù àti ìwà rere wa ṣe ń mú káwọn èèyàn wá jọ́sìn Jèhófà.

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Nígbà àtijọ́, tí wọ́n bá fẹ́ pa ọ̀daràn, wọ́n máa ń kàn wọ́n mọ́ igi. Ṣé bákan náà làwọn ọmọ Ísírẹ́lì ìgbàanì ńṣe?

Ẹ Máa Bá Ara Yín Sọ̀rọ̀ Kẹ́ Ẹ Lè Túbọ̀ Ṣera Yín Lọ́kan

Ó ṣe pàtàkì pé kí tọkọtaya máa bá ara wọn sọ̀rọ̀. Àwọn ànímọ́ wo ló lè mú kí tọkọtaya máa bá ara wọn sọ̀rọ̀ fàlàlà?

Ẹ̀yin Òbí Àtẹ̀yin Ọmọ, Ẹ Máa Bá Ara Yín Sọ̀rọ̀

Àwọn nǹkan wo ni kì í jẹ́ kí ìdílé máa ráyè bá ara wọn sọ̀rọ̀? Kí la lè ṣe láti máa gbọ́ra yé?

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Ohun tó Mú Kí Ìgbésí Ayé Wa Nítumọ̀

Àwọn ọmọ Patricia ní àrùn tí kò wọ́pọ̀. Kẹ́kọ̀ọ́ ohun tó mú kí ìgbésí ayé wọn nítumọ̀ láìka àwọn ìṣòrò tó ń bá wọn fínra.

Ṣe Ìpinnu Tó Dára Kó O Má Báa Pàdánù Ogún Tẹ̀mí Rẹ

Ogún tẹ̀mí wo làwa Kristẹni ní, kí la sì rí kọ́ lára Ísọ̀?

LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA

Wọ́n Dúró Ṣinṣin ní “Wákàtí Ìdánwò”

Kà nípa bí wọ́n ṣe bẹ̀rẹ̀ sí í rí sí àwọn ará wa lọ́dún 1914 nígbà Ogun Àgbáyé Kìíní, nítorí pé wọ́n ò dá sí ọ̀ràn ogun.