Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) April 2013

Kọ́ bó o ṣe lè kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́nà tó gbéṣẹ́ àti bó o ṣe lè máa lo ọgbọ́n Ọlọ́run lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ àti nínú ìgbé ayé rẹ.

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—ní Mẹ́síkò

Kà nípa bí ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀dọ́ ṣe borí àwọn ìṣòro kan kí wọ́n bàa lè ṣe púpọ̀ sí i lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wọn.

Jàǹfààní Kíkún Látinú Kíka Bíbélì Déédéé

Tá a bá ń kà Bíbélì, tá a sì ń fi ohun tá ń kọ́ nínú rẹ̀ sílò, ó máa ṣe wá láǹfààní. Kọ́ bó o ṣe lè máa kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́nà tó gbéṣẹ́.

Fi Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ran Ara Rẹ Àti Àwọn Míì Lọ́wọ́

Ǹjẹ́ o gbà pé Bíbélì ṣe iyebíye? Tó o bá fara balẹ̀ kẹ́kọ̀ọ́ 2 Tímótì 3:16, wàá túbọ̀ gbara lé ẹ̀bùn tí Jèhófà fún wa yìí.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

A Fi Àádọ́ta Ọdún Ṣe Iṣẹ́ Ìsìn Ní Ilẹ̀ Olótùútù

Ka ìtàn arábìnrin Aili àti Annikki Mattila, tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn wọn gẹ́gẹ́ bí aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe ní àríwá orílẹ̀-èdè Finland

Ẹ Máa Wádìí Dájú Àwọn Ohun Tí Ó Ṣe Pàtàkì Jù

Ọlá ńlá ló jẹ́ fún wa pé a wà nínú ètò Ọlọ́run. Báwo la ṣe lè máa kọ́wọ́ ti ètò Ọlọ́run?

Ẹ Má Ṣe Jẹ́ Kí Àárẹ̀ Mú Yín

Báwo la ṣe lè máa bá ètò Ọlọ́run rìn kí ìtara wa má sì dín kù?

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Jésù sọ pé wọ́n máa pa tẹ́ńpìlì Jèhófà run pátápátá. Ǹjẹ́ wọ́n tún tẹ́ńpìlì tó wà ní Jerúsálẹ́mù kọ́ lẹ́yìn ọdún 70 Sànmánì Kristẹni?