Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) March 2013

Ìwé ìròyìn yìí ń rán gbogbo àwa Kristẹni létí pé kò yẹ ká dẹ́kun láti máa sá eré ìje ìyè. Ó kọ wá bá a ṣe lè mọ ohun tó wà nínú ọkàn ìṣàpẹẹrẹ wa àti bá a ṣe lè mọ Ọlọ́run wa, Jèhófà.

‘Kò Sí Ohun Ìkọ̀sẹ̀’ fún Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà

Kí ló túmọ̀ sí pé kò sí ohun ìkọ̀sẹ̀ kankan fún àwọn tó nífẹ̀ẹ́ òfin Jèhófà? Kí ni kò ní jẹ́ kó o dẹ́kun sísá eré ìje ìyè?

Ǹjẹ́ Ó Wù Ẹ́ Láti Mọ Jèhófà?

Ọ̀rọ̀ wòlíì Jeremáyà lè mú kó o ní ọkàn ìṣàpẹẹrẹ tó ń ṣiṣẹ́ dáadáa.

Ní Báyìí Tá A Ti “Wá Mọ Ọlọ́run”—Kí Ló Kàn?

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká máa ṣàyẹ̀wò déédéé bóyá ìgbàgbọ́ àti ìfọkànsìn wa sí Jèhófà ṣì lágbára.

Gba Ìtùnú, Kó O sì Tu Àwọn Míì Nínú

Kò sẹ́ni tí kì í ṣàìsàn. Àìsàn àwọn míì tiẹ̀ le koko gan-an. Tá a bá dojú kọ irú ìṣòro bẹ́ẹ̀, kí la lè ṣe?

Jèhófà Ni Ibùgbé Wa

Bó tilẹ̀ jẹ́ pé inú ayé búburú là ń gbé, kí nìdí tó fi dá wa lójú pé Jèhófà máa dáàbò bo àwọn èèyàn rẹ̀?

Máa Gbé Orúkọ Ńlá Jèhófà Ga

Báwo ló ṣe máa ń rí lára rẹ tó o bá ń lo orúkọ Ọlọ́run? Kí ló túmọ̀ sí láti mọ orúkọ Ọlọ́run àti láti máa rìn ní orúkọ rẹ̀?

Ṣé Josephus Ló Kọ Ọ́ Lóòótọ́?

Ṣé òǹkọ̀wé ìtàn àwọn Júù tó ń jẹ́ Flavius Josephus ló kọ ìwé Testimonium Flavianum?

Má Ṣe Sọ̀rètí Nù!

Má ṣe ronú pé ẹnì kan ò lè wá sin Jèhófà. Kẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn tí kò sọ̀rètí nù àti ìdí tí wọn kò fi ṣe bẹ́ẹ̀.