Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) February 2013

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn ogún tẹ̀mí tí àwa èèyàn Jèhófà ní àti bá a ṣe lè dúró lábẹ́ ààbò Jèhófà.

Èyí Ni Ogún Tẹ̀mí Wa

Tó o bá ń ronú nípa àwọn nǹkan tí Jèhófà ti ṣe fún gbogbo aráyé àtàwọn èèyàn rẹ̀, wàá túbọ̀ mọyì ogún tẹ̀mí wa.

Ǹjẹ́ O Mọyì Ogún Tẹ̀mí Wa?

Tó o bá mọ àwọn ogun tẹ̀mí wa tó o sì mọyì wọn, wàá lè túbọ̀ máa fi ìṣòtítọ́ sin Jèhófà.

Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Olú Ọba Gbọ́ Ìhìn Rere

Pọ́ọ̀lù jẹ́rìí nígbà gbogbo. Kà nípa bí àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù ṣe lè fún ẹ níṣìírí láti máa jẹ́rìí nígbà gbogbo.

Dúró Sí Ibi Ààbò Jèhófà

Kí ni ibi ààbò Jèhófà báwo ni àwọn olùjọsìn Jèhófà ṣe lè rí ààbò níbẹ̀?

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọkàn Rẹ Tàn Ẹ́ Jẹ

Nígbà míì, ọkàn wa lè mú ká máa ṣàwáwí nípa àwọn nǹkan tí kò dáa tá a ṣe. Báwo la ṣe lè mọ ohun tó wà lọ́kàn wa?

Sá Fún Àwọn Nǹkan Tí Kò Ní Jẹ́ Kí Ọlọ́run Dá Ẹ́ Lọ́lá

Kí lo lè ṣe kí Ọlọ́run lè dá ẹ lọ́lá? Kí ló lè mú kí Ọlọ́run má ṣe dá ẹ lọ́lá?

Ibatan Kayafa Ni

Àpótí tí wọ́n kó egungun òkú Míríámù sí tí wọ́n hú jáde jẹ́ ẹ̀rí pé àwọn èèyàn tó gbé ayé lóòótọ́ tí wọ́n sì wà látinú ìdílé kan ni Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn.

LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA

“Ohun Mánigbàgbé” Tó Bọ́ Sákòókò

Kà nípa bí àwòkẹ́kọ̀ọ́ nípa ìṣẹ̀dá ṣe ran àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Jámánì lọ́wọ́ nígbà tí wọ́n ṣenúnibíni sí wọn nígbà Ogun Àgbáyé Kejì.