Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) January 2013

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—ní Norway

Báwo ni ìbéèrè kan tó bá ìdílé kan lójijì ṣe mú kí wọ́n lọ sìn níbi tí wọ́n ti nílò àwọn oníwàásù púpọ̀ sí i?

Jẹ́ Onígboyà, Jèhófà Wà Pẹ̀lú Rẹ!

Wàá jàǹfààní púpọ̀ tó o bá tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jóṣúà, Jèhóádà, Dáníẹ́lì àtàwọn míì tí wọ́n fi ìgbàgbọ́ àti ìgboyà hàn.

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ohunkóhun Mú Ẹ Jìnnà Sí Jèhófà

Àpilẹ̀kọ yìí jíròrò mẹ́ta lára àwọn ohun méje kan tá ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí wọ́n mú wa jìnnà sí Jèhófà. Àwọn ohun ni: iṣẹ́, eré ìdárayá àti ìdílé.

Túbọ̀ Sún Mọ́ Jèhófà

Kí la lè ṣe tí àwọn ẹ̀rọ ìgbàlódé, ọ̀rọ̀ ìlera, owó àti ìgbéraga kò fi ní mú wa jìnnà sí Jèhófà?

O Lè Sin Jèhófà Kó O Má Sì Kábàámọ̀

Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ṣe àwọn àṣìṣe tó lágbára gan-an nígbà ayé rẹ̀, àmọ́ ó tún ṣe àwọn ìpinnu tó mọ́gbọ́n dání. Kí la lè kọ́ lára rẹ̀?

Àwọn Alàgbà Jẹ́ ‘Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ Fún Ìdùnnú Wa’

Àwọn nǹkan wo làwọn alàgbà máa ń ṣe kí inú àwọn ará lè máa dùn lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Ọlọ́run?

Ọmọbìnrin Kan Lo Ìdánúṣe

Ka bí ọmọbìnrin kan tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́wàá lórílẹ̀-èdè Chile ṣe ṣiṣẹ́ kára kó bàa lè pe gbogbo àwọn tó ń sọ èdè Mapudungun sí ìṣẹ̀lẹ̀ pàtàkì kan.