Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Jí!  |  No. 6 2017

Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀

Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀

Kí nìdí tó fi dà bíi pé ayé yìí ti bà jẹ́ kọjá àtúnṣe?

Bíbélì sọ pé: “Kì í ṣe ti ènìyàn tí ń rìn àní láti darí àwọn ìṣísẹ̀ ara rẹ̀.”​—Jeremáyà 10:23.

Ìwé ìròyìn “Jí!” yìí ṣàlàyé ìdí tí ọ̀pọ̀ èèyàn fi gbà pé ayé yìí ṣì ń bọ̀ wá dáa.