Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Jí!  |  No. 6 2017

Atọ́ka Àwọn Àkòrí fún Jí! 2017

Atọ́ka Àwọn Àkòrí fún Jí! 2017

Jí! ni ìwé ìròyìn tó dá lórí oríṣiríṣi nǹkan tó sì délé-dóko jù lọ láyé!

Ó lé ní 360 mílíọ̀nù ẹ̀dà tá à ń tẹ̀ ní ohun tó ju ọgọ́rùn-ún èdè lọ!

ÀJỌṢE ÀWỌN ÈÈYÀN

 • Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Ní Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ (ọmọ títọ́): No. 6

 • Bó O Ṣe Lè Mọyì Ẹnì Kejì Rẹ (ìgbéyàwó): No. 1

 • Ẹ̀rín Músẹ́​—Ẹ̀bùn Tó O Lè Fúnni: No. 1

 • Iṣẹ́ Ilé Ṣe Pàtàkì (ọmọ títọ́), No. 3

 • Kí Làwọn Èèyàn Ń Rí Nínú Eré Tó Léwu? (àwọn ọ̀dọ́): No. 5

 • Nígbà Tí Àwọn Ọmọ Bá Ti Kúrò Nílé (ìgbéyàwó): No. 4

 • Nígbà Tí Òbí Ẹnì Kan Bá Kú (àwọn ọ̀dọ́): No. 2

 • ‘Orúkọ Rere Dára Ju Ọ̀pọ̀ Yanturu Ọrọ̀ Lọ’: No. 4

 • Tí Òbí Ọmọdé Kan Bá Kú: No. 2

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

 • “Irú Ìfẹ́ Yìí Wú Wa Lórí Gan-an Ni” (ìmìtìtì ilẹ̀ lórílẹ̀-èdè Nepal): No. 1

ÀWỌN ẸNI INÚ ÌTÀN

ÀWỌN ẸRANKO ÀTI EWÉKO

Ẹ̀SÌN

 • Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Bíbélì Ti Wá Lóòótọ́? No. 3

ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ

 • Onímọ̀ Nípa Àrùn Ọpọlọ Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́ (Rajesh Kalaria): No. 4

 • Onímọ̀ Nípa Ètò Orí Kọ̀ǹpútà Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́ (Dr. Fan Yu): No. 3

ÌLERA ÀTI ÌTỌ́JÚ

 • Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ní Ìdààmú Ọkàn: No. 1

ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈÈYÀN

OHUN TÓ Ń LỌ LÁYÉ

 • Ṣé Ayé Yìí Ti Bà Jẹ́ Kọjá Àtúnṣe? No. 6

 • Tí Àjálù Bá Ṣẹlẹ̀​​—Ohun Tó O Lè Ṣe Láti Gbẹ̀mí Là: No. 5

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

 • Bó O Ṣe Lè Máa Ṣọ́ Nǹkan Lò: No. 5

 • Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Agbára Abàmì No. 2

 • Ṣé Ọwọ́ Rẹ Máa Ń Dí Jù? No. 4

SÁYẸ́ǸS

 • Èso Pollia: No. 4

 • Ìkarawun Ìṣáwùrú: No. 5

 • Irun Ara Ẹran Omi Tó Ń Jẹ́ Otter: No. 3

 • Ìṣùpọ̀ Iṣan Enteric Nervous System: No. 3

 • Kòkòrò Saharan Silver: No. 1

 • Ọgbọ́n Tí Oyin Fi Ń Bà Lé Nǹkan: No. 2