Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Jí!  |  No. 4 2017

Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀

Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀

Lónìí, ọwọ́ àwọn èèyàn máa ń dí débi pé wọn kì í sábà ráyè fún ẹbí àti ọ̀rẹ́, èyí ló sì máa ń fà á tí àjọṣe wọn pẹ̀lú àwọn ẹlòmíì kì í fi í gún régé.

Báwo la ṣe lè máa lo àkókò wa bó ṣe tọ́?

Ọkùnrin ọlọgbọ́n kan sọ pé: “Ẹ̀kúnwọ́ kan ìsinmi sàn ju ẹ̀kúnwọ́ méjì iṣẹ́ àṣekára àti lílépa ẹ̀fúùfù.”​—Oníwàásù 4:6.

Ìwé ìròyìn “Jí!” yìí sọ bá a ṣe lè lo àkókò wa lọ́nà tí ó tọ́ àti bá a ṣe lè mọ ohun tó yẹ ká fi sí ipò àkọ́kọ́.