Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

JÍ! No. 3 2016 | Bá A Ṣe Borí Ìṣòro Èdè

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń ṣe iṣẹ́ bàǹtà banta láti túmọ̀ èdè.

COVER SUBJECT

Bá A Ṣe Borí Ìṣòro Àtayébáyé

Kí nìdí táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà fi ń túmọ̀ àwọn ìtẹ̀jáde wọn sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èdè?

COVER SUBJECT

Bá A Ṣe Borí Ìṣòro Èdè—Iṣẹ́ Táwọn Atúmọ̀ Èdè Wa Ń Ṣe

Atúmọ̀ èdè kan ṣàlàyé bó ṣe ń ṣe iṣẹ́ rẹ̀.

PORTRAITS FROM THE PAST

Ignaz Semmelweis

Gbogbo ìdílé lónìí ló yẹ kó máa dúpẹ́ lọ́wọ́ ọkùnrin yìí. Kí nìdí?

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Yanjú Ọ̀rọ̀

Ọ̀nà tí ọkùnrin àti obìnrin ń gbà sọ̀rọ̀ yàtọ̀ síra. Tá a bá lóye àwọn ìyàtọ̀ yìí, aáwọ̀ ò ní máa ṣẹlẹ̀ lọ́pọ̀ ìgbà.

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Ìgbàgbọ́

Bíbélì sọ pé ‘láìsí ìgbàgbọ́ kò ṣeé ṣe láti wù Ọlọ́run dáadáa.’ Kí ni ìgbàgbọ́? Báwo lo ṣe lè ní ìgbàgbọ́?

Oúnjẹ Tó Gbòdì Lára Àtèyí Tí Kò Báni Lára Mu—Ṣó Yàtọ̀ Síra??

Ewu wo ló wà nínú kéèyàn fúnra rẹ̀ pinnu èyí tó ń ṣe òun?

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Ọrùn Èèrà

Báwo ni èèrà ṣe ń gbé nǹkan tó wúwo ju òun fúnra rẹ̀ lọ?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì