Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Jí!  |  No. 2 2017

Ṣé Ó Wù Ẹ́ Kó O Mọ Bíbélì Dáadáa?

Ṣé Ó Wù Ẹ́ Kó O Mọ Bíbélì Dáadáa?

Kò pọn dandan kó o ní

  • Ọgbọ́n àrà ọ̀tọ̀

  • Owó

  • Tàbí kó o kàn gba ohun tí wọ́n bá ti sọ gbọ́

Ohun tó o nílò

  • “Agbára ìmọnúúrò.”Róòmù 12:1

  • Ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀

Àwọn ohun tó o máa kọ́ nínú Bíbélì máa yà ẹ́ lẹ́nu.

Mọ Púpọ̀ Sí I

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Tó O Ní Nípa Bíbélì!

Mọ ohun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìbéèrè nípa Ọlọ́run, Jésù, ìdílé, ìjìyà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

BÉÈRÈ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

Bíbélì ń ran ọ̀pọ̀ mílíọ̀nù èèyàn lọ́wọ́ kárí ayé láti rí ìdáhùn sáwọn ìbéèrè tó ṣe pàtàkì jù lọ. Ṣé wàá fẹ́ jẹ́ ọ̀kan lára wọn?