Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ No. 2 2016 | Kí Nìdí Tí Jésù Fi Jìyà Tó Sì Kú?

Àǹfààní wo ni ikú ọkùnrin kan ní 2,000 ọdún lè ṣe fún wa lónìí?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ṣé Lóòótọ́ Ló Ṣẹlẹ̀?

Kí ló mú káwọn àkọsílẹ̀ ìwé Ìhìn Rere jẹ́ òótọ́?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Nìdí Tí Jésù Fi Jìyà Tó sì Kú?

Báwo ni ikú rẹ̀ ṣe ṣe wá láǹfààní?

Ṣé Ó Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Lọ Jọ́sìn ní Ojúbọ?

Ọ̀pọ̀ àwọn ìsìn lónìí ló ní ojúbọ. Ṣé àǹfààní kankan wà nínú jíjọ́sìn níbẹ̀?

Gbígba Ìkìlọ̀ Lè Kó Ẹ Yọ Nínú Ewu!

Àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì sọ nípa àjálù tó rọ̀ dẹ̀dẹ̀. Ṣé wàá gba ìkìlọ̀?

Orí àti Ẹsẹ—Ta Ló Fi Wọ́n Sínú Bíbélì?

Kí nìdí tí ọ̀nà tí wọ́n gbà pín Bíbélì yìí fi gbéṣẹ́?

Tá ni Èṣù?

Ǹjẹ́ Èṣù lè darí àwọn èèyàn?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Orí Àgbélébùú Ni Jésù Kú Sí?

Àmì tí àwọn èèyàn fi ń dá àwọn Kristẹni mọ̀ ni ọ̀pọ̀ èèyàn ka àgbélébùú sí. Ṣe ó yẹ ká máa lò ó nínú ìjọsìn?