Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ No. 1 2016 | Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Olóòótọ́?

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló jẹ́ pé tí wọ́n bá sọ̀rọ̀ fún ìṣẹ́jú mẹ́wàá, ó kéré tán irọ́ kan á wà níbẹ̀. Ṣé dandan ni ká dá yàtọ̀?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ṣé Jíjẹ́ Olóòótọ́ Ṣì Bóde Mu?

Ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Hitoshi lè mú ká ronú bẹ́ẹ̀.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Àkóbá Tí Ìwà Àìṣòótọ́ Lè Ṣe fún Ẹ

Mọ ohun tí irọ́ jẹ́.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Àǹfààní Tó Wà Nínú Jíjẹ́ Olóòótọ́

Ohun tó ṣẹlẹ̀ sáwọn kan jẹ́ ká rí àǹfààní tó wà nínú jíjẹ́ olóòótọ́.

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Fún Mi Ní Ayọ̀ àti Ìbàlẹ̀ Ọkàn fún Ọdún Kan Péré

Ohun tó wà nínú 1 Jòhánù 1:9 wọ Alain Broggio lọ́kàn gan-an.

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Láyé àtijọ́, báwo ni wọ́n ṣe ń ṣe àkájọ ìwé, báwo sì ni wọ́n ṣe ń lò ó? Àwọn wo ló ṣeé ṣe kó wà lára “àwọn olórí àlùfáà” tá a mẹ́nu kàn nínú Bíbélì?

Ohun Tó O Lè Ṣe Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé O Kò Já Mọ́ Nǹkan Kan

Ohun mẹ́ta tó o lè ṣe láti níyì lójú ara wa.

Ọ̀RỌ̀ ỌGBỌ́N TÓ WÚLÒ LÓDE ÒNÍ

Má Ṣe Máa Ṣàníyàn

Yàtọ̀ sí pé Jésù ní ká dẹ́kun ṣíṣàníyàn, ó tún ṣàlàyé bá a ṣe lè ṣe é.

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ǹjẹ́ àwọn òkú lè jíǹde?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ǹjẹ́ Bíbélì Lè Ràn Mí Lọ́wọ́ Tí Mo Bá Ní Ìrẹ̀wẹ̀sì Ọkàn?

Àwọn ohun mẹ́ta kan wà tí Ọlọ́run máa ń fún wa ká lè fara da ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn.