Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) March 2016

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti May 2 sí May 29, 2016 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

Ṣé O Lè Ran Ìjọ Rẹ Lọ́wọ́?

Ṣé o lè máa lo ìtara bíi tàwọn míṣọ́nnárì kódà nínú ìjọ tó o wà?

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ṣé Ẹ Ti Múra Tán Láti Ṣe Ìrìbọmi?

Àwọn ìbéèrè mẹ́ta kan lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti ṣèpinnu.

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Báwo Lẹ Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ fún Ìrìbọmi?

Kí lo lè ṣe bó bá ń ṣe ẹ́ bíi pé o ò tí ì múra tán láti ṣèrìbọmi tàbí tó wù ẹ́ láti ṣèrìbọmi àmọ́ táwọn òbí ẹ ní kó o mú sùúrù díẹ̀?

Báwo Lo Ṣe Lè Pa Kún Ìṣọ̀kan Tó Wà Láàárín Àwa Kristẹni?

Ìran kan tó wà nínú Ìṣípayá orí 9 jẹ́ ká rí bó ti ṣe pàtàkì tó pé ká ṣera wa lọ́kan.

Jèhófà Ń Tọ́ Wa Sọ́nà Ká Lè Jogún Ìyè

Báwo la ṣe lè jẹ́ kí Jèhófà máa tọ́ wa sọ́nà?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Ìgbà wo ni Bábílónì Ńlá mú àwọn èèyàn Ọlọ́run nígbèkùn? Ṣé tẹ́ńpìlì gangan ni Sátánì mú Jésù lọ nígbà tó dán Jésù wò?