Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) January 2016

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti February 29 sí April 3, 2016 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

“Ẹ Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Ará Tí Ẹ Ní Máa Bá A Lọ”!

Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wa ti ọdún 2016 lè ràn wá lọ́wọ́ láti múra sílẹ̀ de àwọn ohun tó máa tó ṣẹlẹ̀.

Jẹ́ Kí ‘Ẹ̀bùn Ọ̀fẹ́ Aláìṣeé-Ṣàpèjúwe’ Ti Ọlọ́run Mú Ẹ Lọ́ranyàn

Báwo ni ìfẹ́ tí Ọlọ́run ní sí wa ṣe ń mú ká máa tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù pẹ́kípẹ́kí, báwo ló sì ṣe ń mú ká máa fìfẹ́ hàn sáwọn ará wa ká sì máa dárí ji àwọn tó ṣẹ̀ wá?

Ẹ̀mí Ń Jẹ́rìí Pẹ̀lú Ẹ̀mí Wa

Kí ló túmọ̀ sí pé kí Ọlọ́run fẹ̀mí yan ẹnì kan? Báwo ni Ọlọ́run ṣe ń fẹ̀mí yan èèyàn?

“Àwa Yóò Bá Yín Lọ”

Kí ló yẹ ká máa fi sọ́kàn nípa àwọn 144,000?

À Ń Láyọ̀ Bá A Ṣe Ń Bá Ọlọ́run Ṣiṣẹ́

Báwo ni bíbá Ọlọ́run ṣiṣẹ́ ṣe ń mú ká láyọ̀, báwo ló sì ṣe ń dáàbò bò àjọṣe tá a ní pẹ̀lú rẹ̀?