Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) February 2016

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti April 4 sí May 1, 2016 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

Jèhófà Pè É Ní “Ọ̀rẹ́ Mi”

Ṣé ó wù ẹ́ kó o dọ̀rẹ́ Jèhófà? Àpẹẹrẹ Ábúráhámù máa jẹ́ kó o mọ bó o ṣe lè dọ̀rẹ́ Jèhófà.

Máa Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà

Báwo ni Rúùtù, Hesekáyà àti Màríà ṣe ní àjọṣe tímọ́tímọ́ pẹ̀lú Ọlọ́run?

Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà

Ọ̀nà mẹ́rin kan wà tí àpẹẹrẹ Jónátánì lè gbà ràn wá lọ́wọ́ láti jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà tá a bá níṣòro tó le koko.

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ìránṣẹ́ Jèhófà Tó Jẹ́ Adúróṣinṣin

Báwo ni Dáfídì, Jónátánì, Nátánì àti Húṣáì ṣe fi hàn pé ohun tó ṣe pàtàkì jù ni pé káwọn jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà?

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Jèhófà Ti Jẹ́ Kí N Ṣàṣeyọrí Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Rẹ̀

Ọdún 73 ni Corwin Robison fi sin Ọlọ́run tọkàntọkàn, ó sì lé ní 60 ọdún tó lò ní Bẹ́tẹ́lì tó wà lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.

Máa Fayọ̀ Sin Jèhófà

Àwọn ìlànà mẹ́ta wo ló yẹ kó o máa ronú lé lórí kó o lè máa fayọ̀ sin Jèhófà?