Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) April 2016

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti May 30 sí June 26, 2016 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

Tá A Bá Jẹ́ Olóòótọ́, A Máa Rí Ojúure Ọlọ́run

Ẹ̀kọ́ wo làwa Kristẹni kọ́ látinú ohun tí Bíbélì sọ nípa Jẹ́fútà àti ọmọbìnrin rẹ̀?

“Ẹ Jẹ́ Kí Ìfaradà Ṣe Iṣẹ́ Rẹ̀ Pé Pérépéré”

Kí ló yẹ ká máa rántí tá a bá ń kojú àdánwò? Àpẹẹrẹ àwọn tó lo ìfaradà wo ló máa ràn ẹ́ lọ́wọ́?

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Pé Jọ Láti Jọ́sìn?

Tó o bá ń lọ sípàdé, wàá jàǹfààní, wàá ṣe àwọn mí ì láǹfààní, inú Jèhófà á sì dùn. Lọ́nà wo?

Má Ṣe Dá Sí Ọ̀rọ̀ Òṣèlú Tàbí Ogun

Ohun mẹ́rin tó máa jẹ́ kó o mọ ohun tó o lè ṣe bí wọ́n bá fẹ́ fipá mú ẹ dá sí ọ̀rọ̀ òṣèlú tàbí ogun.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Àwọn Obìnrin Ajẹ́jẹ̀ẹ́ Ìnìkàngbé Di Ìránṣẹ́ Jèhófà

Kí ló mú kí wọ́n kúrò ní ilé àwọn ajẹ́jẹ̀ẹ́ ìnìkàngbé, tí wọ́n sì fi ẹ̀sìn Kátólí ìkì sílẹ̀?

Ṣé Bí Ìrì Ni Iṣẹ́ Ìwàásù Rẹ Rí?

Báwo lo ṣe lè mú kí iṣẹ́ ìwàásù rẹ wọ àwọn èèyàn lọ́kàn, kó tù wọ́n lára, kó sì gbẹ̀mí wọ́n là?