Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) August 2016

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti September 26 sí October 23, 2016 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Mo Láyọ̀ Pé Mò Ń Lo Ara Mi Lẹ́nu Iṣẹ́ Ọlọ́run

Ọ̀dọ́kùnrin kan tó wá láti orílẹ̀-èdè England bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ míṣọ́nárì lórílẹ̀-èdè Puerto Rico, iṣẹ́ tó sì fún un láyọ̀ jù lọ nìyẹn.

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Ṣètò Ìgbéyàwó?

Ṣé lóòótọ́ la lè sọ pé ẹ̀bùn ni ìgbéyàwó jẹ́ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run?

Ohun Táá Jẹ́ Kí Tọkọtaya Bára Wọn Kalẹ́

Ohun tó lè yanjú ìṣòro ẹ wà nínú Bíbélì.

Máa Wá Ohun Tó Sàn Ju Góòlù Lọ

Mọ ọ̀nà mẹ́ta táwọn tó ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lè gbà dà bí àwọn tó ń wa góòlù.

Ǹjẹ́ O Lè Fi Kún Ohun Tó Ò Ń Ṣe Nínú Ìjọsìn Ọlọ́run?

Kọ́ àwọn ohun tó o lè ṣe láti fi kún ohun tó ò ń ṣe nínú ìjọsìn rẹ.

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dá Àwọn Míì Lẹ́kọ̀ọ́?

Àwọn nǹkan wo lo lè ní káwọn akéde tuntun máa lé?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Kí ló dé táwọn ọ̀tá Jésù fi ranrí mọ́ ọ̀rọ̀ fífọ ọwọ́?

LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA

“Iṣẹ́ Ìwàásù Mi Ń Sèso Rere, Ó sì Ń Fògo fún Jèhófà”

Bó ti lẹ̀ jẹ́ pé àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ò lóye àwọn ìlànà Bíbélì nípa ogun dáadáa nígbà ogun àgbáyé kìíní, síbẹ̀ ìwà wọn àti ìṣesí wọn sèso rere.