Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) May 2017

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti July 3 sí 30, 2017 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

Bá A Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ Fáwọn Ọmọ Tí Òbí Wọn Jẹ́ Àjèjì

Tí ìwọ àtàwọn ọmọ rẹ bá ti ṣí lọ sílùú mí ì, báwo lo ṣe lè ran àwọn ọmọ rẹ lọ́wọ́ kí òtítọ́ lè jinlẹ̀ nínú wọn? Báwo làwọn mí ì ṣe lè ṣèrànwọ́?

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Bí Mo Tiẹ̀ Jẹ́ Adití, Mò Ń Kọ́ Àwọn Mí ì Lẹ́kọ̀ọ́

Bó tilẹ̀ jẹ́ pé adití ni Walter Markin, síbẹ̀ ó rí ayọ̀ àti ìbùkún lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà.

Ẹ Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Yín Di Tútù

Àwọn Kristẹni kan ní ọgọ́rùn-⁠ún ọdún kìíní jẹ́ kí ìfẹ́ wọn di tútù. Kí la lè ṣe táá jẹ́ kí ìfẹ́ tá a ní fún Jèhófà túbọ̀ lágbára?

“Ìwọ Ha Nífẹ̀ẹ́ Mi Ju Ìwọ̀nyí Lọ Bí?”

Jésù jẹ́ kí Símónì Pétérù mọ ohun tó yẹ kó gbawájú láyé rẹ̀. Ṣé àwa náà lè fi ẹ̀kọ́ yìí sílò lónìí?

Bí Gáyọ́sì Ṣe Ran Àwọn Ará Lọ́wọ́

Ta ni Gáyọ́sì, kí sì nìdí tó fi yẹ ká tẹ̀ lé àpẹẹrẹ rẹ̀?

Ayọ̀ Tó Wà Nínú Kéèyàn Jẹ́ Kí Ohun Ìní Díẹ̀ Tẹ́ Òun Lọ́rùn

Kí ló mú kí tọkọtaya kan dín ohun ìní wọn kù? Báwo ni wọ́n ṣe ṣe é? Báwo ni ìpinnu yìí ṣe fún wọn láyọ̀?

LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA

“Wọ́n Fìtara Wàásù Pẹ̀lú Ìfẹ́ Ọkàn Tó Ju Ti Tẹ́lẹ̀ Lọ”

Lẹ́yìn àpéjọ tó wáyé lọ́dún 1922, báwo làwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ṣe tẹ̀ lé ìtọ́ni náà pé kí wọ́n “fọn rere Ọba náà àti Ìjọba rẹ̀”?