Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́) June 2018

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti August 6 sí September 2, 2018 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

“Ìjọba Mi Kì Í Ṣe Apá Kan Ayé Yìí”

Jésù ò dá sí ọ̀rọ̀ òṣèlú nígbà tó wà láyé, ẹ̀kọ́ wo nìyẹn kọ́ wa lónìí?

Ká Jẹ́ Ọ̀kan Bí Jèhófà àti Jésù Ṣe Jẹ́ Ọ̀kan

Báwo nìwọ náà ṣe lè ṣe ipa tìrẹ káwa èèyàn Ọlọ́run lè túbọ̀ wà níṣọ̀kan?

Ó Pàdánù Ojú Rere Ọlọ́run

Àpẹẹrẹ Rèhóbóámù ọba Júdà jẹ́ ká mọ ohun tí Ọlọ́run ń béèrè lọ́wọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan wa.

Máa Fi Àwọn Òfin àti Ìlànà Jèhófà Kọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ

Ọlọ́run ti fún wa ní ẹ̀rí ọkàn, àmọ́ a gbọ́dọ̀ kọ́ ọ kó lè darí wa síbi tó yẹ.

Ẹ Jẹ́ “Kí Ìmọ́lẹ̀ Yín Máa Tàn” Kẹ́ Ẹ Lè Fògo fún Jèhófà

Iṣẹ́ ìwàásù nìkan kọ́ ló ń jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ wa tàn.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Gbogbo Ìgbà Ni Jèhófà Máa Ń Tù Mí Nínú

Edward Bazely kojú ìṣòro ìdílé, wọ́n ta kò ó torí ohun tó gbà gbọ́, òun fúnra rẹ̀ ṣàṣìṣe, ó sì rẹ̀wẹ̀sì.

Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Kí Àwọn Èèyàn

Bó jẹ́ “ẹ-ǹ-lẹ́ o” lásán la ṣe, a lè múnú àwọn mí ì dún.

Ǹjẹ́ O Rántí?

Ṣé o lè dáhùn àwọn ìbéèrè tó dá lórí àwọn àpilẹ̀kọ tó wà nínú àwọn Ilé Ìṣọ́ tó jáde láìpẹ́ yìí?